Anthony Chinasa
Anthony Chinasa | |
---|---|
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Labour Party |
Anthony Chinasa-Abiola jẹ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asofin ìpínlè Abia . O n ṣe aṣoju Àgbègbè Ìpínlẹ̀ arin gbùngbùn ti Umuahia labẹ ẹgbẹ òṣèlú Labour Party (LP). [1]
Igbesi aye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Anthony Chinasa ni a bi ni Ibeku, Ìpínlẹ̀ Abia, orílè-èdè Nàìjíríà. Pẹlu awon erongba ti won so mọ orúkọ re wípé Yorùbá ni, Pẹlu orúkọ abiso tin je “Abiola,” o salaye nínú iforowanilenuwo kan to wáyé lodun 2023 pe ìran Igbo loun je, ti àwọn òbí méjèèjì si ti wa láti Ibeku. Inagijẹ naa "Abiola" ni a gba ni iṣọkan pẹlu ore òṣèlú rẹ, Gbadebo Rhodes-Vivour, lákòókò idibo 2023. [2]
Ni ọdun 2023, Chinasa jawe olubori lati ṣoju ẹkun arin gbùngbùn ipinlẹ Umuahia ni Ile ìgbìmò aṣofin ipinlẹ Abia. Nṣiṣẹ labẹ Ẹgbẹ òṣèlú Labour, ipolongo rẹ tẹnumọ akoyawo, ilowosi àgbègbè, ati atunṣe isofin. [3] [4]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://abiastate.gov.ng/house-of-assembly/
- ↑ https://www.lindaikejisblog.com/2023/3/i-am-not-a-yoruba-man-lp-candidate-anthony-chinasa-abiola-who-won-a-seat-in-the-abia-state-house-of-assembly-says-video-2.html
- ↑ https://www.ngnews247.com/anthony-chinasa-abiola-biography-wikipedia-age-tribe-parents-net-worth/
- ↑ https://www.tvcnews.tv/2023/03/candidate-anthony-chinasa-denies-abiola-name-in-abia/