Gbadebo Rhodes-Vivour
Ìrísí
Gbadebo Chinedu Patrick Rhodes-Vivour | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gbadebo Chinedu Patrick Rhodes-Vivour 8 Oṣù Kẹta 1983 Lagos Island, Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | |
Political party | Labour Party (2022–present) |
Movement | Nigerians Against GMO |
Olólùfẹ́ | Ifeyinwa Aniebo |
Parent(s) |
|
Àwọn olùbátan |
|
Website | grvlagos.com |
Gbadebo Chinedu Patrick Rhodes-Vivour, ti a tun mo si GRV, ni won bi ni ojo kejo osu keta, odun 1983. O keko imo sayensi gboye nipa ayaworian ile, o je ajijagbara omoniyan ati oloselu. O dije dupo gomina ipinle Eko ni abe asia egbe oselu Labour Party ninu idije ti odun 2023 ti o padanu si owo Gomina ti o wa lori oye lowo Babajide Sanwo-Olu.[1][2] Oun kan naa ni o dije dupo asoju ile igbimo asofin apa iwoOorun ipinle Eko labe asia egbe oselu Peoples Democratic Party ni odun 2019.[3][4][5][6]
Àwọn itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Oluwafemi, Ayodele (10 August 2022). "Substitution Primary: LP elects Gbadebo Rhodes-Vivour as Lagos Guber Candidate". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Iniobong, Iwok (5 September 2022). "LP unveils Rhodes-Vivour as Lagos Guber Candidate". Business Day (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ "Why I Am On A Mission To Free Lagos West – Gbadebo Rhodes Vivour". Vanguard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 22 November 2018.
- ↑ Akinseye, Isabella (22 November 2018). "Isabella Akinseye Talks To Lagos Senatorial Candidate Gbadebo Rhodes-Vivour On Politico Politica, Watch". Bella Naija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Olafusi, Ebunoluwa (25 October 2018). "35-year-old MIT Graduate From Ikeja Wins PDP Ticket In Lagos West Senatorial District". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ "Gbadebo Rhodes-Vivour: The Man for a New Lagos". Vanguard. 2 March 2023.