Antonio Gramsci
Appearance
Antonio Gramsci | |
---|---|
Antonio Gramsci | |
Orúkọ | Antonio Gramsci |
Ìbí | Ales, Sardinia | Oṣù Kínní 22, 1891
Aláìsí | April 27, 1937 Rome, Italy | (ọmọ ọdún 46)
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Marxism |
Ìjẹlógún gangan | Politics, Ideology, Culture |
Àròwá pàtàkì | Hegemony, Organic Intellectual, War of Position |
Ìpa lórí
Louis Althusser, Zygmunt Bauman, Judith Butler, Noam Chomsky, Robert W. Cox, Paulo Freire, Stuart Hall, Eric Hobsbawm, Ernesto Laclau, Chantal Mouffe, Michael Parenti, Edward Said, Domenico Losurdo, Palmiro Togliatti, Cornel West, Alain de Benoist, Umberto Eco, Raymond Williams , Jalal Al-e-Ahmad, Néstor García Canclini, Giovanni Arrighi
|
Antonio Gramsci (Àdàkọ:IPA-it) (January 22, 1891 – April 27, 1937) je was an amoye ara Itali, olukowe, oloselu ati oniro oloselu. O je ikan ninu awon oludasile ati olori Egbe Komunisti ile Itali ,o je jiju si ogba ewa latowo ijoba Fasisti Benito Mussolini. Awon iwe kiko re da le lori ituyewo asa ati isolori oloselu. O se pataki gege bi aronu ogidi ninu asa Marksisti. O gbajumo fun ajotunmo hegemoni asa gege bi ona ti orileijoba ninu awujo kapitalisti, be na sini won gba bi akopa koko ninu imoye.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |