Arinzo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Arinzo jẹ́ fíìmù Nàìjíríà tí a ṣe ní ọdún 2013, láti ọwọ́ Iyabo Ojo. Wọ́n ṣàfihàn àwọn òṣèré láti orílẹ̀-èdè Ghana àti Nàìjíríà nínú fíìmù yìí. Orílẹ̀-èdè Ghana àti Nàìjíríà bákan náà ni wọ́n ti ya fíìmù náà.[1]

Arinzo
Olùgbékalẹ̀Iyabo Ojo
Déètì àgbéjáde2013
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba

Ìsọníṣókí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fíìmù náà dá lórí àwọn ọmọbìnrin méjì tó jẹ́ ọmọ ìyá kan náà tí ìbáṣepọ̀ wọn ò dán mọ́rán nítorí ọ̀kan jẹ́ ọlọ́pàá, tí èkejì sì jẹ́ adigunjalè. Nínú eré náà, àwọn ọmọbìnrin méjèèjì di ọ̀tá ara wọn nítorí ìhà tí oníkálùkùú jọ kọ sí ayé.[1]

Àwọn akópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àmì-ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n yan Iyabo Ojo fún àmì-ẹ̀yẹ YMAA gẹ́gẹ́ bí i olú ẹ̀dá-ìtàn.[4][5]

Tún wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Nollywood Tangos: Iyabo Ojo Vs Laide Bakare". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-06. Retrieved 2022-07-29. 
  2. "Actress Iyabo Ojo steps up, moves into palatial residence". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-15. Retrieved 2022-07-29. 
  3. Orenuga, Adenike (2014-01-24). "Iyabo Ojo set to drop estranged husband's name". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29. 
  4. "Dailytrust News, Sports and Business, Politics | Dailytrust". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29. 
  5. Ayobami, Abimbola (2013-05-27). "Top Yoruba actors' battle to win at the Yoruba Movie Academy Awards". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.