Femi Branch
Appearance
Femi Branch | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | David Babafemi Mauton Osunkoya 14 Oṣù Kàrún 1970 Sagamu, Ogun, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1991–present |
Gbajúmọ̀ fún | Author of 409 page Anthology of Fifty Poems and Three Plays titled FROM SENBORA published in Dec. 2010 Producer/Writer of the Movie AWAY FROM HOME (2005) |
Notable work | FROM SENBORA - an Anthology of Fifty Poems and Three Plays |
Ọmọ ìlú | Odosenbora |
Àwọn ọmọ | Two |
Parent(s) | Ọ̀túba Gbolade & Chief Mrs Modúpẹ́ Ọ̀ṣúnkọ̀yà |
Àwọn olùbátan | Barr. Olugboyega Osunkoya, Apostle John Benhotons |
Awards | Special Recognition Award, Ambassadors O. A. U. Ile Ife, Actor of the Year, Moshood Abiola Polytechnic, Ogun State, Special Recognition Award, University of Illorin, African Youth Council Special Recognition. |
Website | www.femibranch.com |
Fẹ́mi Babáfẹ́mi Branch ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Karùn ún, ọdún 1970 (14-5-1970). Jẹ́ òṣèré Orí-ìtàgé, Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì,olùkọ̀tàn àti akọ ewì àpilẹ̀kọ , adarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1][2]
Ibẹ́rẹ́ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Fẹ́mi ní ìlú Ṣàgámù ní ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ògùn, sínú ẹbí Ọ̀ṣúnkọ̀yà ní ọdún 1970. Ṣùgbọ́n wọ́n ṣẹ̀ wá láti ìlú Odòṣẹ̀ńbora ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ilá Oòrùn Ìjẹ̀bú. [3] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ́ Satellite Town ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Amúwó Ọ̀dọ̀fin,ní Ìpìlẹ̀ Èkó, ṣáájù kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Girama Airforce ní Ìkejà.[4] Lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ níbití ó ti ó ti gba ìwé ẹ̀rí akọ́kọ́ nínú ìmọ Eré Oníṣe.[5]
Àwọn Ìtaọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "TOP ACTOR FEMI BRANCH OPENS UP ON N4M DEBT SCANDAL". nigeriafilms.com. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "Nollywood Actor, Femi Branch Play Host @ Miss Insurance Grand Finale -- article". dailytimes.com.ng. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ Tolu. "Nollywood Actor, Femi Branch, Battles Serious Spiritual Problem…". INFORMATION NIGERIA. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "Femi Branch: How Acting Affects Family Life, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "I have a ministry, but Im not a pastor -Femi Branch". modernghana.com. Retrieved 25 February 2015.