Sagamu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sagamu

Orisagamu
LGA
Agbègbè Araromi
Agbègbè Araromi
Sagamu is located in Nigeria
Sagamu
Sagamu
Location in Nigeria
Coordinates: 6°50′N 3°39′E / 6.833°N 3.650°E / 6.833; 3.650Coordinates: 6°50′N 3°39′E / 6.833°N 3.650°E / 6.833; 3.650
Country Nigeria
StateOgun State
LGA(s)Sagamu
Government
 • Local Government ChairmanOdulate Olashile (APC)
Area
 • Total614 km2 (237 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total253,412
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
121[1]
ISO 3166 codeNG.OG.SH
National languageYorùbá
Lua error in Module:Mapframe at line 289: attempt to perform arithmetic on local 'lat_d' (a nil value).

Sagamu tàbí Ishagamu jẹ́ ìlú àti olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ kan tí ó wà ní apá Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn Ìpìnlẹ̀ Ògùn lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Ibu.[2] Sagamu sì jẹ́ àkójọpọ̀ ìlú mẹ́tàlá ní ìpínlẹ̀ Ògùn lọ́nà odò Ibu àti odò Ewuru, láàrin ipinle Eko àti Ibadan. Wọ́n sì dasílẹ̀ láàrin sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún nípa sẹ̀ ọmọ-ẹgbẹ́ Yorùbá,[3]ní apá Guusu Ìwọ̀-oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwọn ìlú mẹ́tàlá tí ó wà nínú rẹ̀ ni: Makun, Ofin Sonyindo, Epe, Ibido, Igbepa, Ado, Oko, Ipoji, Batoro, Ijoku, Latawa ati Ijagba.[4][5] Ó sì jẹ́ olú-ìlú Rẹ́mo, ẹni tí ó jẹ́ apàṣẹ ìlú Remo ni a mọ̀ sí Oba Akarigbo. Ìlú Ofin sì ni ààfin Ọba Akarigbo wà.

Àwọn èèyàn tó lààmìlaaka láti ìlú Sagamu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn àtòjọ àwòrán ìlú Sagamu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Basil Ugorji (2012). From Cultural Justice to Inter-Ethnic Mediation: A Reflection on the Possibility of Ethno-Religious Mediation in Africa. Basil Ugorji. pp. 95–. ISBN 978-1-4327-8835-3. http://books.google.com/books?id=FQjQe-nCkzIC&pg=PA95. 
  3. "Shagamu | Nigeria". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-15. 
  4. "Shagamu time now. Local current time and time zone in Shagamu / Ogun / Nigeria - Current-Time.World". current-time.world (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-25. 
  5. "Remo Town in Ogun Nigeria Guide". www.nigeriagalleria.com. Retrieved 2020-05-25.