Jump to content

Asimina parviflora

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Taxonomy not available for Asimina; please create it automated assistant
Asimina parviflora
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/AsiminaAsimina parviflora
(Michaux) Dunal

Asimina parviflora, ti o tun n jẹ smallflower pawpaw, ni ó jẹ́ igi eléso kékeré tí ó jẹ́ ìkan lára custard apple

Asimina parviflora
Scientific classification Edit this classification
Kingdom: Plantae
Clade: Tracheophytes
Clade: Angiosperms
Clade: Magnoliids
Order: Magnoliales
Family: Annonaceae
Genus: Asimina
Species:
A. parviflora
Binomial name
Asimina parviflora

(Michaux) Dunal

Àwọn ibi tí a ti lè ri

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A le ri igi yi ni apá Guusu ìlà oòrùn Orílẹ̀ èdè America, láàárín ìlú TexasVirginia . Igi yi saba ma n hu si àgbègbè tí iyanrìn bá pọ̀ sí jùlọ àti ibi tí àwọn igi gbígbẹ bá wà. [2]

Igi èso Asimina parvifloraomi aró maroon, tí àwọn òdòdó orí rẹ̀ sì ma ń nípọn páá pàá jùlọ nígbà ti òjò bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ nínú ọduń. Ó ma ń so èso tí ó fara jọ èso ìbẹ́pẹ tí a lè jẹ, ṣugbọn èso rẹ kéré ju ti ìbẹ́pẹ lọ.

Àwọn eruku òdòdó rẹ̀ ma ń fọ́nká sílẹ̀ lásìkò tí ó bá ń gbaradì láti so èso. A tún lè ri ní apá gúúsù àwọn ìlú tí a ti mẹ́nu bà lókè yí jù àwọn ìbẹ́pẹ gangan lọ. Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ, igi èso parviflora kìí fi bẹ́ẹ̀ ga púpọ̀, wọn kìí ga ju ìwọn ẹsẹ̀ bàtà méta lọ, díẹ̀ lára wọn ni ó ma ń ga ju ẹgbẹ́ lo. Àwọn òdòdó rẹ̀ kíí sábà fẹ̀ ju ìwọ̀n sẹ̀ntímítà méjì lọ. Òdòdó rẹ̀ ni ó kọ́kọ́ ma ń bẹ̀rẹ̀ pèlú àwọ̀ omi búráùn, yóò sì tún di aláwọ̀ ewé nígbà tí ó bá ń dàgbà, yóò sì yí padà sí àwọ̀ màrúnùn nígbà tí ó bá ti gbó tán.

Àwọn ewé jẹ́ aláwọ̀ ewé dúdú nígbàgbogbo, àti dídán ní sojurigindin. [3]

A. parviflora hybridizes ni imurasilẹ pẹlu A. triloba lati ṣe agbekalẹ Asimina ×piedmontana .

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Botanic Gardens Conservation International (BGCI); IUCN SSC Global Tree Specialist Group (2019). "Asimina parviflora". The IUCN Red List of Threatened Species (IUCN) 208: e.T143321751A143321753.. doi:10.2305/IUCN.UK.2019-1.RLTS.T143321751A143321753.en.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "iucn" defined multiple times with different content
  2. Flora of North America
  3. Walker JW (1971) Pollen Morphology, Phytogeography, and Phylogeny of the Annonaceae.