Jump to content

Bísí Kọ́mọláfẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bísí Kọ́mọláfẹ́
Ọjọ́ìbíBísí Kọ́mọláfẹ́ Veronica
1986
Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Aláìsí31 December 2012
University College Hospital, Ibadan
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́2008–2012

Bísí Kọ́mọláfẹ́, tí a bí ní inú ọdún 1986 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùdarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bísi di ìlú-mòọ́ká lẹ́yìn tí ó kópa nínú eré Ìgboro ti Dàrú àti Aramotu Igboro Ti Daru and Aramotu.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bísi ni ó jẹ́ àbílé kejì àwọ òbí rẹ̀ nínú àwọn ọmọ márùn ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí ní ìlú ÌbàdànÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìlú Ìbàdàn kan náà.[2] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó (LASU) níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú Business Administration.[3][4]

Bísí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ tí ó sì di ìlú-mòọ́ká nínú eré oníṣẹ́ nígbà tí ó kópa nínú eré Ìgboro ti dàrú, àti ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olú ẹ̀dá ìtàn nínú eré Bólóde ò kú, Àṣírí owó, Èbúté, Ẹja tútù atu Ọká. Bisi's acting career shot into limelight after she starred in the movie Igboro Ti Daru. She went on to play leading roles in films including Bolode O'ku, Asiri Owo and Ebute.[5] She was nominated in the "Revelation of The Year" category at the 2009 Best of Nollywood Awards and in the "Best Lead Actress in a Yoruba film" category at the 2012 edition.[6]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọ́rí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Amì-ẹ̀yẹ Àpèjúwe amì-ẹ̀yẹ Èsì
2009 2009 Best of Nollywood Awards Revelation of The Year Wọ́n pèé[6]
2012 2012 Best of Nollywood Awards Best Lead Actress in a Yoruba film Wọ́n pèé[7]

Bísí Kọ́mọláfẹ́ gbàgboro kan ní ọjọ́ Kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2012. Ó papò dà látàrí ipò ìlóyún tí ó wà, gẹ́gẹ́ bí gbogbo àwọn Ìwé-ìròyìn ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀. [8][9][10] Ó papò dà ní ilé ìwòsàn ìkọ́ni ti ìlúÌbàdàn tí wọ́n sì sin-ín ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kíní ọdún 2013. [11] in Ibadan.[12]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Igboro Ti Daru
  • Aye Ore Meji
  • Apere Ori
  • Omo Olomo Larin Ero
  • Jo Kin Jo
  • Akun
  • Bolode O'ku
  • Aramotu
  • Asiri Owo
  • Ogbe Inu
  • Aiyekooto
  • Latonwa
  • Alakada
  • Mofe Jayo
  • Ebute
  • Iberu Bojo

Kọ́mọláfẹ́ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Túndé Ìjàdùnọlá tí ó fi orílẹ̀-èdè Canada ṣe ibùgbé, amọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. [13]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Nollywood actress, Bisi Komolafe, for burial in Ibadan, tomorrow". Vanguard. 3 January 2013. http://www.vanguardngr.com/2013/01/nollywood-actress-bisi-komolafe-for-burial-in-ibadan-tomorrow/. Retrieved 25 August 2015. 
  2. "Untold Story Of Bisi Komolafe’s Mysterious Death - She Died Of Spiritual Attack". MJ Celebrity Magazine. 2015-03-27. Archived from the original on 2015-03-27. Retrieved 2022-02-01. 
  3. Akinnagbe Akintomide (3 January 2013). "PICTURES: THE UNTOLD STORY ABOUT THE MYSTERIOUS DEATH OF MOVIE STAR BISI KOMOLAFE". Nigeria Films. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 25 August 2015. 
  4. "Bisi Komolafe biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2020-09-30. 
  5. Bayo Adetutu (1 January 2013). "Bisi Komolafe, Nollywood actress dies". P.M. News. http://www.pmnewsnigeria.com/2013/01/01/bisi-komolafe-nollywood-actress-dies/. Retrieved 25 August 2015. 
  6. 6.0 6.1 "Best of Nollywood Awards 2009". BellaNaija. 7 December 2009. Retrieved 25 August 2015. 
  7. "Best of Nollywood Awards: List of Nominees". Nollywood by Mindspace. 2014-10-15. Archived from the original on 2014-10-15. Retrieved 2022-02-01. 
  8. Oseyiza Ogbodo (28 December 2013). "January 2013 HIGHLIGHTS: Bisi Komolafe dies". National Mirror. Archived from the original on 24 August 2014. https://web.archive.org/web/20140824094034/http://nationalmirroronline.net/new/january-2013-highlights-bisi-komolafe-dies/. Retrieved 25 August 2015. 
  9. "Bisi Komolafe's Doctor speaks about her cause of death". Africa Spotlight. January 13, 2013. Archived from the original on 2017-01-04. https://web.archive.org/web/20170104163630/http://africanspotlight.com/2013/01/07/bisi-komolafes-doctor-speaks-about-her-cause-of-death/. Retrieved 26 August 2015. 
  10. Ebun Sessou (12 January 2013). "Bisi Komolafe’s property tears fiancé, family apart". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2013/01/bisi-komolafes-property-tears-fiance-family-apart/. Retrieved 25 August 2015. 
  11. Ola Ajayi (4 January 2013). "Tears as Bisi Komolafe goes home". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2013/01/tears-as-bisi-komolafe-goes-home/. Retrieved 25 August 2015. 
  12. Akinwale Aboluwade (January 5, 2013). "Nollywood actress, Bisi Komolafe, buried amid tears". The Punch. Archived from the original on 24 September 2015. https://web.archive.org/web/20150924130824/http://www.punchng.com/news/nollywood-actress-bisi-komolafe-buried-amid/. Retrieved 25 August 2015. 
  13. "Bisi Komolafe biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2020-09-30. 

Àdàkọ:Authority control