Jump to content

Bọ́sẹ̀ Àlàó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Notability

Ìwé-alàyé[ìdá]
Bọ́sé Àlàó
Ọjọ́ìbíJanuary 6, 1985 (1985-01-06) (ọmọ ọdún 39)
Ìpínlẹ̀ Èkó,
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànBose Alao
Bosslady
BAO
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • Actor
  • filmmaker
  • producer
  • endorsement model
  • entrepreneur
Ìgbà iṣẹ́2003–present

Bọ́sẹ̀ Àlàó Ọmọtóyọ̀sí tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kíní ọdún 1985, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùdarí eré, ,ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Bọ́sẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó sì jẹ́ àbílé kẹrin nínú ẹbí rẹ̀. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Command àti ilé-ẹ̀kó girama ti ti Gedions Comprehwnsive High School ní ọdún 2002.. Ó té siwájú ní inú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní inú ọgba Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó kọ́ ẹ̀kọ́ ní Biology, àmọ́ ó fagilé ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ níbẹ̀ lẹ́yìn látàrí tí ó ṣe ètò mọ̀mí-n- mọ̀ ọ́, tí sì bí àwọn ọmọ rẹ̀ tí kò sì lè padà sẹ́nu ẹ̀kọ́ rẹ̀ mọ́. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Lagos Srate City Polytechnic Ìkẹja ní Ìpínlẹ̀ Èkó, tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí dípúlọ́mà nínú ìmọ̀ Business Administaration.

Iṣẹ́ rẹ̀ bí òṣèré

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bọ́sẹ̀ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òṣèré Nollywood, olùgbéré-jáde tó dántọ́ .[2] Ó di ìlú-mòọ́ká látara ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Ìtàkùn]].

Bọ́sẹ̀ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọ̀gbẹ́ni oníṣòwò kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Razak Ọmọ́tóyọ̀sí tí wọ́n sì bí ọmọ obìnrin mẹ́rin fúnra wọn.

Àwọn àṣàyàn.eré.rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ìmọ̀ràn Ìkà(2006)
  • Opa Abo(2007)
  • Ọláṣùbòmí(2011)
  • Bòmíláṣírí'(2013)
  • Rivers Between(2014)
  • Rough Day(2016)
  • Blindspots(2016)

Àwọn eré tí ó ti gbé jáde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Zafaa Awards United Kingdom 2011(Best Actress)[3]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Fíìmù Ipa tí ó kó Notes
2007 Mo Ń ọ̀ wá Ọlọ́run
2013 Wanabe "Halima Abubakar's friend"
2015 Ìjọ̀gbọ̀n "Bidemi, Femi Adebayo's controversial wife"
2016 Super Dad "Nadia"
2015 Rivers between "Bridget the 1st daughter"
2016 Rough Day "Olivia Julliet Ibrahim's Rival"
2006 Òkò Àṣá "Young Bukky Wright "
2006 Edge of Paradise "Lab Attendant" "Directed by Creg Odutayo - an MNET Production"
2016 Torment "Titi, a snitch to Ebere Mcniwizu"
2016 Ìmọ̀ràn Ìkà "Georgina"
2016 Thorny "Georgina" " With Ebube Nwagbo, Frank Artus and Eucheria Anunobi"
2014 Papa ajasco "Pepeye's friend" "Produced by Wale Adenuga"
2011 Oníkọlà "a female that refused circumcision"
2007 Opa Abo "Moriyike "
2014 Bòmíláṣírí "Adeola"
2006 Ìtàkùn "Daughter to Racheal Oniga & Moyosore Olutayo"
2010 Ọláṣùbòmí' "Olasubomi"

Ẹ tún wo àwọn òṣèré bíi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Bose Alao out with Rivers Between". The Nation. Retrieved 12 October 2016. 
  2. "Actress and wife of footballer, Bose Alao Omotoyossi bags first endorsement deal". NET. Archived from the original on 29 October 2016. Retrieved 12 October 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Zafaa Honours Indigenous African Movie Makers In Ghana". Ghana MMA. Archived from the original on 13 October 2016. Retrieved 12 October 2016. 

Àdàkọ:Authority control