Babalola Chinedum Peace

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Professor
Babalola Chinedum Peace
FAAS, FAS
Professor Babalola Chinedum Peace.jpg
IbùgbéIbadan
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaObafemi Awolowo University, Ile Ife
Iṣẹ́Pharmacist
Academics
Educational administrator
Ìgbà iṣẹ́1980 - present
Gbajúmọ̀ fúnPharmacy
Pharmacokinetics
Pharmacodynamics
PK/PD
Voice Note
( Wiki Loves Women Radio Interview)

Babalola Chinedum Peace (née Anyabuike) FAS, FAAS wà nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Nàìjíríà  tó jẹ́ inímọ̀ nípa egbò igi Pharmacy, tó tún jẹ́ obinrin àkọ́kọ́ elégbògi ìbílẹ̀ Fásítì ìlú Ìbàdàn.

Iṣẹ́ ìwádìí rẹ̀ dá lórí àtúpalẹ̀ oògùn drug analysis (PK/PD pharmacogenetics), (pharmacogenomics), (pharmaceutical analysis) pẹ̀lú (bioethics).

Owun ni adaari agba Faculty of Pharmacy and principal investigator ti University of Ibadan Centre for Drug discovery, development and production.[1]

Lára àwọn ìdàgbàsókè tó ṣe ni High-performance liquid chromatography ọ̀nà ìtúpọ̀ quinine nínú biometrics. Àgbékalẹ̀ yí lórí àtúpọ̀ quinine jẹ́ kí ètò pharmacokinetics yè nípa quinine ní Africans tó fa ìpìlẹ̀ ìwọ̀n ìlò bí a ṣe lè mu oògùn akọ ibà fún aláìsàn.

Ètò ìwádìí bí ǹkan ṣe ṣẹ̀ lóríoògùn àti bi àwọn ómọ ogún ara ṣe ń gba agbára àti bí wọ́n ṣr ń lòó tí a mọ̀ sí metabolism, ni ó mú àbá Idiwóku wá lóri bioavailability pẹ̀lú iṣẹ́ bakitéríà dí ẹ̀ nínú àwọn antibàọ́tíìkì nígb tí a báko pọ̀ pẹ̀lú àwọn oògùn alátakò ibà.(anti-malaria).[2]

Ọ̀kan nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì ni Babalọlá Chinedum Peace tó mú ìròyìn àkọ́kọ́ wá lótí ẹ̀kọ́ pharmacogenetic tòun ti ìléra àti àwọn tó ń da àwọn aláìsàn láàmú lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà pẹ̀lú (pro-guanil) gẹ́gẹ́ bí ìbéèrè. Ìròyìn yí mú àwọn ojúlówó abà wá pé díẹ̀ nínú ọmọ Nàjíríà ní àìsàn (mutant CYP2C19 genes) àti àìkọbi ara sí iṣẹ́ ọwọ oògùn iṣe lọ́pọ̀ (metabolizer).[3]

Wọ́n yan Babalọlá gẹ́gẹ́ bí olórí gíwá kejì ní ilé ẹ̀kọ́ Vice Chancellor ti Chrisland University, ní oṣù Bélú (November), ọ̀dún 2017,Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà.[4]

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]