Bad Boy Timz
Ìrísí
Bad Boy Timz | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Olorunyomi Oloruntimilehin |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Bad Boy Timz |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹjọ 1999 Lagos |
Irú orin | Afrobeats |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2019 – present |
Labels | Shock Absorbers Music |
Associated acts |
Olorunyomi Oloruntimilehin (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Kẹjọ ọdún 1999) tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ Bad Boy Timz jẹ́ olórin olórin ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó kọ orin "MJ,"[1] àti àtúnkọ orin náà pẹ̀lú Mayorkun.
Olamide ṣàfihàn rẹ̀ nínú orin rẹ̀, tí í ṣe Loading off Carpe Diem[2], tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ Rookie of the Year ní The Headies 2020.[3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2019, àwọn orin àti ijó Bad Boy Timz tí àọn ènìyàn ń kan sárá sí bọ sí gbàgedè ojú-ìwòrán fún ilé-iṣẹ́ olórin kan, ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2019, wọ́n pè é kí ó wá tọwọ́ bọ ìwé àṣẹ pẹ̀lú wọn.[4]
Ní ọdún 2020, Bad Boy Timz kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní Bells University of Technology, pẹ̀lú oyè ẹ̀kọ́ nínú Computer Engineering.
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]EP
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Timz EP[5]
Àwọn orin àdákọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ìtọ́ka |
---|---|---|
2019 | "Hustle" | |
"Complete Me" | [6] | |
2020 | "MJ" | |
"MJ Remix" (featuring Mayorkun) | [7] | |
"Have Fun" | [8] | |
"MJ Remix" (featuring Teni) | ||
2021 | "Move" | [9] |
“Oasis” | ||
“Skelele” (featuring Olamide) | [10] |
Gẹ́gẹ́ bí i olórin tí wọ́n ṣàfihàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Olùgbéjáde | Àwo-orin | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2020 | "Loading"(Olamide) | P.Prime | Carpe Diem | |
2020 | "Denge Pose" (Dandizzy) | Rage | ||
2021 | "Complicationship"(Tanasha Donna) | [11] | ||
2022 | "Faaji"(Blaqbonez|1da Banton) | |||
2024 | “Grace” (Donny Crown) | [1] |
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀bùn | Olùgbà | Èsì | Ref(s) |
---|---|---|---|---|---|
2020 | City People Entertainment Awards | Best New Act | "Himself" | rowspan=2 Gbàá | [12] |
The Headies, The Rookies | Rookie of the Year | [13] | |||
2021 | Net Honours | Most played Hip Hop song | "Loading" (Olamide featuring Bad Boy Timz) | Wọ́n pèé | [14] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "10 Nigerian Artistes To Watch In 2021". 27 December 2020. Retrieved 28 April 2021.
- ↑ "Bad Boy Timz". Retrieved 28 April 2021.
- ↑ "How Bad Boy Timz Won The Award For Rookie Of The Year At Headies Explore". 22 February 2021. Retrieved 16 March 2021.
- ↑ "As up-and-coming artiste, I attended events without performing –Bad Boy Timz". 28 March 2020. Retrieved 28 April 2021.
- ↑ "Album: Timz EP by Bad Boy Timz". Retrieved 1 December 2021.
- ↑ "Bad Boy Timz – "Complete Me"". 12 November 2019. Retrieved 3 January 2022.
- ↑ "[Music] Bad Boy Timz Ft. Mayorkun – MJ (Remix)". 19 June 2020. Retrieved 3 January 2022.
- ↑ "Bad Boy Timz – "Have Fun"". 6 November 2020. Retrieved 3 January 2022.
- ↑ "New Music: Bad Boy Timz – Move". 24 October 2021. Retrieved 1 December 2021.
- ↑ "Bad boy timz Skelele ft Olamide". 24 May 2021. Retrieved 3 January 2022.
- ↑ "Complicationship (feat. Badboy Timz)". 30 October 2021. Retrieved 3 January 2022.
- ↑ "Winners emerge at 2020 City People music awards". Citypeopleonline.com. 7 December 2020.
- ↑ "The Headies 2021: Fireboy, Omah Lay, Bad Boy Timz win first-ever award [See list of winners]". 22 February 2021. Retrieved 28 April 2021.
- ↑ "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07.