Battle on Buka Street
Battle on Buka Street | |
---|---|
Fáìlì:Battle on Buka Street Poster.jpg Promotional poster | |
Adarí | Funke Akindele Tobi Makinde |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele Nicole Ofoegbu FilmOne Studio |
Òǹkọ̀wé | Funke Akindele Jack'enneth Opukeme Stephen Oluboyo Jemine Edukugbe |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Mercy Johnson Sola Sobowale Tina Mba Nkem Owoh Femi Jacobs Kelvin Ikeduba |
Orin | Martinsfeelz Adam Songbird Tolu Obanro Kleb Shout Yomi Olabisi Simi Dada |
Ìyàwòrán sinimá | Adeoluwa 'Captain Dezgy' Owu |
Olóòtú | Valentine Chukwuma |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Funke Ayotunde Akindele Network (FAAN) |
Olùpín | FilmOne Distribution |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 140 Minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English, Yoruba, Igbo, Hausa, Nigerian Pidgin |
Owó àrígbàwọlé | ₦668,423,056[1] |
Battle on Buka Street jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí Funke Akindele àti Tobi Makinde darí.
[2]Funke Ayotunde Akindele (FAAN) àti FilmOne Studios ló pawọ́ pọ̀ ṣagbátẹrù fíìmù yìí.[3] Wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù yìí ní ọjọ́ 16, oṣù kejìlá ọdún 2022, tó sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àríwísí. Fíìmù náà di àseyọrí ńlá, tí wọ́n sì pa owó rẹpẹtẹ lórí rẹ̀.[4]
Ìsọníṣókí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]̀Àhunpọ̀ ìtàn náà dá lórí ìjà láàárín obìnrin méjì tó ń jìjàkadì nínú ìdíje oúnjẹ sísè, láti lè di 'King of Buka Street', èyí to jẹ́ oyè tí wọ́n máa ń fún olóúnjẹ tó dára jù lọ ní agbègbè náà.[5][6]
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Funke Akindele gẹ́gẹ́ bí i Yejide[7]
- Mercy Johnson gẹ́gẹ́ bí i Awele
- Sola Sobowale gẹ́gẹ́ bí i Asake
- Tina Mba gẹ́gẹ́ bí i bi Ezinne
- Nkem Owoh gẹ́gẹ́ bí i Maduka
- Femi Jacobs gẹ́gẹ́ bí i Lanshile
- Kelvin Ikeduba gẹ́gẹ́ bí i Chukwuemka
- Sani Musa Danja gẹ́gẹ́ bí i Kazeem
- Bimbo Ademoye gẹ́gẹ́ bí i Asake kékeré
- Uche Obunse gẹ́gẹ́ bí i Ifunnaya
- Moshood Fattah gẹ́gẹ́ bí i Ademide
- Judith Ushi gẹ́gẹ́ bí i Fadekami
- Gbemi Akinlade gẹ́gẹ́ bí i Kaira
- Iyanu Gabriel gẹ́gẹ́ bí i Kaiso
- Mike Afolarin
- Wumi Toriola gẹ́gẹ́ bí i ọ̀rẹ́ Yedije ore kìíní
- Regina Chukwu gẹ́gẹ́ bí i ọ̀rẹ́ Yedije ore kejì
Ìṣàgbéjáde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù yìí jẹ́ fíìmù àgbéléwò ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Funke Akindele jẹ́ olùdarí fún, lẹ́yìn tó darí Your Excellency àti Omo Ghetto: The Saga.[8] Ó ṣeé ṣe kí èyí jẹ́ fíìmù àṣekágbá rẹ̀ nítorí ó ti pinnu láti dara pọ̀ mọ́ òṣèlú, àti láti kópa nínú ìdìbo ti ọdún 2023.[9]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà àti èyí tí wọ́n yàn án fún
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Àbájáde | Ìtọ́kasí |
---|---|---|---|---|---|
2023 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress In A Comedy/TV Series | Mercy Johnson | Wọ́n pèé | [10] |
Funke Akindele | Wọ́n pèé | ||||
Best Actor In A Comedy/TV Series | Nkem Owoh | Wọ́n pèé | |||
Best Art Director | Olatunji Afolayan | Wọ́n pèé | |||
Best Picture Editor | Valentine Chukwuma | Wọ́n pèé | |||
Best Sound Editor | Kolade Morakinyo & Pius Fatoke | Wọ́n pèé | |||
Best Sound Track | Gbas Gbos by Tolu Obanro & Adam Songbird | Wọ́n pèé | |||
Best Make Up | Hakeem Effects Onilogbo & Jemila Sedik | Wọ́n pèé | |||
Best Writer | Funke Akindele, Jack'enneth Opukeme, Stephen Oluboyo & Jemine Edukugho | Wọ́n pèé | |||
Best Overall Movie | Funke Akindele | Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Top 20 films 9th - 11th December 2022 - Cinema Exhibitors Association of Nigeria". www.ceanigeria.com.
- ↑ Eze, Chinelo (2023-04-18). "Funke Akindele Reacts; As Battle On Buka Street Gets 10 Nominations". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-03.
- ↑ Abdul-Hafeez, Adedimeji Quayyim (2022-11-22). "Funke Akindele releases trailer for 'Battle on Buka Street'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-03.
- ↑ Oboh (2022-12-27). "Funke Akindele's 'Battle on Buka Street' sets Nollywood record with N135m in one day". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-31.
- ↑ Abdul-Hafeez, Adedimeji Quayyim (2022-11-28). "6 Nigerian movies you should watch out for this December". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-03.
- ↑ "Akindele's 'Battle On Buka Street' becomes Nollywood's highest-grossing film with N640m". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-02-18. Retrieved 2023-06-03.
- ↑ "Battle on Buka Street - Daily Trust". dailytrust.com. Retrieved 2023-06-03.
- ↑ "Funke Akindele Drops Teaser for 'Battle on Buka Street' – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-12-03.
- ↑ "Funke Akindele: Battle on the Buka Street is a farewell project". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-17. Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]