Bissara
Bissara, tí wọ́n tún máa ń pè ní bessara, besarah, bayssara , bayssar àti tamarakt [1][2] jẹ́ oúnjẹ ní àwọn ará Egypt àti àwọn ará Morocco.[3][4][5] Oúnjẹ náà kún fún fava beans, àlùbọ́sà, gálìkì, ewébẹ̀ òòjọ́ àti amọ́bẹ̀dùn. Gbogbo ohun èlò ní ó máa ń di fífi ara balẹ̀ sè tí wọn yóò sì di lílọ̀ papọ̀ láti lè mú òórùn dídùn tàbí oúnjẹ jáde.
Ní ancient Jewish cuisine, oúnjẹ tí ó fara pẹ́ ẹ , tí a mọ̀ sí "mikpah ful" ní rabbinic literature, ni ó sábàá máa ń di jíjẹ.[6]
Ìpìlẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn onímọ̀ nípa oúnjẹ gbàgbọ́ pé orúkọ Bissara wá láti Ancient Egyptian Ọ̀rọ̀ Hieroglyphic "Bisourou" (tàbí bissouro), èyí tí ó túmọ̀ sí "ẹ̀wà ṣíṣè ".[7][8][9][10][11]
Ṣíṣè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bissara máa ń lo puréed broad beans gẹ́gẹ́ bí ohun èlò pàtàkì.[12][13][14][15] Àfikún ohun èlò ni gálìkì, olive oil, lemon juice, ata gígùn , cumin, àti iyọ̀.[12][16] Bissara máa ń di ṣíṣè nígbà mìíràn nípa lílo split peas tàbí chickpeas.[17]
Oúnjẹ àwọn Egyptian
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní Egypt, bissara máa ń di jíjẹ dáadáa gẹ́gẹ́ bí ìtìbọ̀ fún búrẹ́dì , ó sì máa ń di jíjẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ àárọ̀ , gẹ́gẹ́ bí meze, tàbí ní ẹ̀kọ̀ọ̀kan, fún oúnjẹ ọ̀sán tàbí alẹ́. Bissara Egyptian kún fún àgbo tàbí ewé, ata gígún, omi ọ̀sán, àti ní ẹ̀kọ̀ọ̀kan àlùbọ́sà.[18] oúnjẹ àwọn àgbẹ̀ tí ó wà nínú oko ni ó kẹlẹ̀ jẹ́,[18] bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti gbajúmọ̀ ní ìlú Egypt láti ọdún 2011 nítorí ó dára jù ti èyí tí ó wà ní ìlú lọ, ful medames.[19] kò wọ́n rárá, ó sì ti di ṣíṣe àpèjúwe gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ pauper's.[20]
Oúnjẹ Moroccan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní Morocco, bissara gbájúmọ̀ ní àkókò òtútù ọdún náà, ó sì lè di rírí ní igun mẹ́rin ìlú àti ní orísìírísìí ojú ọ̀nà .[21][22][23] Ó máa ń di bíbù sínú abọ́ tàbí abọ́ ọbẹ̀, tí wọn yóò sì fi òróró ólífì sí i, paprika, àti cumin.[24] Nígbà mìíràn wọ́n máa ń ti búrẹ́dì bọ inú oúnjẹ náà, àti omi òrom̀bó máa ń di fífi sí i.
Àwọn oúnjẹ tí ó jọ ọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tova Dickstein, akọ́sẹ́mọsẹ́ nínú oúnjẹ ìwáṣẹ̀, so oúnjẹ ìwáṣẹ̀ Jewish tí a mọ̀ sí mikpah tàbí mikpah ful, sọ ní ọ̀pọ̀ ìgbà nínú rabbinic literature, sí bissara ìgbàlódé . Orísun ìwáṣẹ̀ ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ oúnjẹ tí a ṣe láti ara ẹ̀wà, gálíkì, míǹtì, àti òróró ólífì. Látàrí fífi ara hàn ní òòrèkóòrè ní Mishnah, ní èyí tó tún kún fún halakhic rule tí ó sọ pé sukkah lè di pípatì lásìkò òjò lọ́wọ́ kan tí mikpah bá ti tútù tí ó sì ń rùn, ó pè é ní "national dish" tí àwọn èèyàn ìgbà ìwáṣẹ̀ ti Israelites.[25]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bissara, Egyptian Vegan Dip of Split Fava Beans, البصارة المصرية, 22 February 2022, retrieved 2 August 2023
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMorse 1998 p. 63
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWeiss Chirichigno 2007
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedKitchen 2010
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedEngineers 2006
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWeiss Chirichigno 20072
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedValenta 2016
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMorse 1998 p. 632
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedStaff 2013
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedVeganDip2
- ↑ 12.0 12.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWeiss Chirichigno 20073
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedValenta 20162
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMorse 1998 p. 633
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedStaff 20132
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedHal Hamon Barbey 2013
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedIndependent.ie 2014
- ↑ 18.0 18.1 كريم, محمد (2015-11-08). "البصارة... وجبة الشتاء الزهيدة" (in ar). العربي. https://www.alaraby.co.uk/miscellaneous/2015/11/8/البصارة-وجبة-الشتاء-الزهيدة.
- ↑ El-Wardani, Lina (2010-05-05). "An Ancient Diet". http://www.egyptindependent.com/ancient-diet/.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedHonnor 2012
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedValenta 20163
- ↑ "Bissara, le plat chaud anti-froid". www.babmagazine.ma. Archived from the original on 2021-12-27. Retrieved 2021-12-27.
- ↑ Rosa., Amar (2 November 2017). Cuisine juive marocaine: la cuisine de Rosa. Editions Gisserot. ISBN 978-2-7558-0763-9. OCLC 1013172477.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedJaffrey 2014
- ↑ Dickstein, Tova (2021) (in he). The Taste of Ancient Israel: Tales of Food and Recipes from the Land of Israel. Israel: Ofir Bikkurim. pp. 86–88.