Bolanle Austen-Peters

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bolanle Austen-Peters
Bolanle Austen-Peters.jpg
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kejì 1969 (1969-02-04) (ọmọ ọdún 54)
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
 • Director
 • Producer
 • Lawyer
OrganizationTerra Kulture & BAP Productions
Olólùfẹ́Adegboyega Austen-Peters
Parent(s)
Websitebolaaustenpeters.com

Bolanle Austen-Peters (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹ́rin, oṣù kejì ọdún 1969), jẹ́ olùdarí Fíìmù/Tíátà Nàìjíríà àti Agbẹjọ́rò.[2][3] Òun tún ni Olùdásílẹ̀ àti Olùdarí fún Terra Kulture, ilé-iṣẹ́ tó ń ṣètò nípa àṣà tó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó .[4] ilé-iṣẹ́ fíìmù àti tíátà rẹ̀, BAP Productions, tí ṣe Atọ́kùn fún àwọn ètò orin bíi: Saro The Musical, Wakaa The Musical,[5] Moremi The Musical, Fela àti the Kalakuta Queens,[6] The Oluronbi Musical,[7][8] àti èyí tí wọ́́ ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe Death and The King's Horseman. Ilé-iṣẹ́ náà ti ṣe Atọ́kùn àwọn fíìmù bíi 93 Days, Bling Lagosians, Collision Course, àti Man of God.[9][10][11][12] Ó wà ní ìbásẹpọ̀ pẹ̀lú Google Arts & Culture ilé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tó máa ń ṣe àkójọjọ̀ ohun ìgbàanì fún Terrakulture lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì .[13]

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó fẹ́ Adegboyega Austen-Peters,[14] pẹ̀lú ọmọ méjì.

Àwọn oyè rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award Category Work Result Ref
2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Movie West Africa Collision Course Àdàkọ:Winner [15]
Best Overall Movie Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀
Best Director Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Meet The Terra Kulture Team". Terrakulture. February 17, 2022. Retrieved May 23, 2022. 
 2. ""Everybody knows at least one person who has been affected by SARS"". Businessday NG. November 20, 2021. Retrieved May 23, 2022. 
 3. "Bolanle Austen-Peters speaks on ‘ Man of God’". Vanguard News. April 23, 2022. Retrieved May 23, 2022. 
 4. Ibukun Awosika (2009). The "Girl" Entrepreneurs. Xulon Press. pp. 47–61. ISBN 9781607915072. https://books.google.com/books?id=RYyk8XIbQDAC&dq=Bolanle+Austen+Peters&pg=PA47. 
 5. "Stage sensation "Wakaa!" becomes first Nigerian musical to hit London". CNN. Retrieved 16 March 2016. 
 6. "Fela and the Kalakuta Queens musical coming to SA". Music in Africa. Retrieved 21 February 2019. 
 7. "Bolanle Austen-Peters Production & MTN Bring Oluronbi Musical To Life". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 12 January 2021. 
 8. Ige, Rotimi (January 21, 2022). "Bolanle Austen-Peters: Celebrating the ‘Queen’ of African theatre". Tribune Online. Retrieved May 23, 2022. 
 9. Correspondents, Our (April 16, 2022). "Bolanle Austen-Peters’ Man Of God Movie To Be Released On Netflix Today". Independent Newspaper Nigeria. Retrieved May 23, 2022. 
 10. Nigeria, Guardian (April 16, 2022). "Bolanle Austen-Peters’ Man of God comes on Netflix". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved May 23, 2022. 
 11. "Bolanle Austen-Peters premieres ‘Man Of God’ - Punch Newspapers". Punch Newspapers. April 15, 2022. Retrieved May 23, 2022. 
 12. "Bolanle Austen-Peters’ ‘Man Of God’ for Netflix Release". THISDAYLIVE. April 15, 2022. Retrieved May 23, 2022. 
 13. "Google, Terra Kulture partner to showcase Nigerian arts and culture". This is Lagos. Retrieved 26 May 2021. 
 14. "Bolanle Austen-Peters steps out with hubby". The Punch. http://www.punchng.com/spice/society/bolanle-austen-peters-steps-out-with-hubby/. 
 15. "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.