Ibukun Awosika

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ibukun Awosika
Ọjọ́ìbí Bilkisu Abiodun Motunrayo Omobolanle Adekola
Oṣù Kejìlá 24, 1962 (1962-12-24) (ọmọ ọdún 56)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdè Nigerian
Orúkọ míràn Blessing Ibukun Awosika
Alma mater
Iṣẹ́
Years active 1989–present
Employer First Bank of Nigeria
Organization SOKOA Chair Centre Limited
Television Business – His Way
Board member of Women in Management, Business and Public Service
Spouse(s) Abiodun Awosika
Children 3
Website ibukunawosika.org

Ìbùkún Abiọ́dún Awóṣìkà (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Bilkisu Abíọ́dú Motúnráyọ̀ Ọmọbọ́láńlé Adékọ́lá ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlél)ógún oṣù Kejìlá ọdún 1962)jẹ́ ọmọ orílé-èdè Nàìjíríà, ó jẹ́ oníṣòwò, oǹkọ̀wé àti às)ọ̀rọ̀gbaninímọ́ràn. Òun ni Alága ilé ìfowópamọ́ First Bank of Nigeria lọ́wọ́́lọ́wọ́.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]