Omobola Johnson
Dr. Omobola Johnson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹfà 1963 London, United Kingdom |
Ẹ̀kọ́ | University of Manchester King's College London |
Office | Honorary Chairperson, Alliance for Affordable Internet (A4AI) |
Ọmọbọla Olubusọla Johnson (bii ni ọjọ kẹjidinlọgbọn oṣu kefa ọdun 1967) je omo orile ede Naijiria. O je ikan ninu awon oni imo tekinology, oun pelu si ni alaga egbe Alliance for Affordable Internet (A4AI).[1][2][3][4][5] O je ojise isọrọ tekinology tele ni abe akoso olori orile ede Goodluck Jonathan.[6] [7][8][9][10][11].
Eto ekọ re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O ka iwe ni ile-eko International School Ibadan, o si se eko giga re ni University of Manchester ninu Electrical and Electronics Engineering.[12] O lọ se masters degree re ni King's College ni ilu London. O gba doctorate degree re ni Cranfield University ninu Business Administration.[13][14]
Ise
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọbọla je oludari fun ile ise Accenture ni Naijiria ki o to di minisita isọrọ tekinology.[15] O beere si ni sise fun Accenture ni odun 1985 ni igba ti ile-ise naa si n je Andersen Consulting. Ọmọbọla je adari ero ibanisoro tekinology eyi ti won da sile lati se iyipada ni ijoba nijiria. [16] Ọmọbọla wa ninu awọn to da egbe obirin WIMBIZ ni odun 2001.[17] O ti gba ọpọlọpọ iyin lati ọdọ awọn ara ilu lati igba ti o ti di ojise ijọba ni ọdun 2011.[18] Ikan ninu awon aseyọri re ni ifilọle ti NigComSat-IR Satellite[19]. Ni igba ti o wa ni ipo ojise, ẹẹdẹgbẹrin ero komputa ni o fi ranse si awọn ile ekọ ni inu eto ti o pe ni School Access Programme (SAP).[20][21][22]
Ni ọdun 2013, ni osu karun, Ọmọbọla fun olori orile ede Goodluck Jonathan ni eto National Broadband Plan fun ọdun 2013 de ọdun 2018.[23]
Ni osu kesan ọdun 2013, orile ede fi Ọmọbọla si ipo adari fun ise awon ojise imo ijinle ati tekinology ti orile ede apapọ[24]
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "a4ai welcomes Dr. Omobola Johnson as new honorary chair".
- ↑ Published. "Ex-minister, Mobola Johnson, seeks equal opportunities for career women". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Vanguard newspaper – Page 213 – Channels Television". Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Indigenous operators condemn government’s low patronage". guardian.ng. Archived from the original on 2022-10-12. Retrieved 2020-05-23. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Foreign debt: Nigeria, other debtor countries, at risk, IMF warns". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-17. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Omobola Johnson". Omobola Johnson – World Economic Forum.
- ↑ Published. "Telecom operators seek executive order to stop multiple taxes". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Buhari unfair to ministers - Omobola Johnson". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-09-17. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ editor (2019-06-20). "Ex-minister Harps on Gender Inclusion". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Ex-minister fumes over N29,000 'crazy bill' for power not used". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-22. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ Published. "Johnson, Alli joins MTN in board shake-up". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Omobola Johnson". World Bank Live (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-29. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Omobola Johnson". cranfield.ac.uk.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2014-02-28. Retrieved 2020-05-01.
- ↑ "LLA 50 leading ladies in corporate Nigeria". guardian.ng. Archived from the original on 2022-05-02. Retrieved 2020-05-23. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Super User. "About the Ministry". commtech.gov.ng. Archived from the original on 2023-08-04. Retrieved 2020-05-01.
- ↑ "Omobola Johnson commends Sterling Bank’s high-level gender inclusion". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-20. Archived from the original on 2020-11-30. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Digitization'll place Nigeria on global map — Johnson". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-03-03. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ NIGCOMSAT LTD. "Nigeria Communications Satellite LTD". nigcomsat.com.
- ↑ Boss Africa. "Boss Africa Magazine – Nigerian Women at the Top : Omobola Johnson Olubusola Honorable Minister of Communication Technology". bossafricamagazine.com. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2020-05-01.
- ↑ "We've linked 27 universities, 1,552 schools, 1.45m students to internet — FG". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-03-20. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "Indigenous operators condemn government’s low patronage". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-05. Archived from the original on 2021-02-24. Retrieved 2020-05-23.
- ↑ "FG TO PARTNER WITH IRELAND ON ICT INNOVATION". www.commtech.gov.ng. Archived from the original on 2018-12-15. Retrieved 2018-12-15.
- ↑ http://www.dailytrust.com.ng/top-stories/5334-ministers-fired-in-target-of-rebel-govs