Jump to content

Grace Alele-Williams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Grace Alele-Williams OON, FMAN, FNAE (tí a bí ní ọjọ kẹrìndínlógún ti oṣù kejìlá ọdún 1932, tí ó sì fi àyé sílè ní March 25, 2022) jé òjògbón nínú ìmò Mathi nígbà ayé rè [1], Grace Alele-Williams ní orúko ní ìtàn, o jé obinrin àkókó tí o gbà àmì eye Dokita ni Nàìjíríà, o sì jé obinrin àkókò tí ódi olori ilé-ìwé yunifásitì ní Nàìjirià [2], Grace Alele jé olori yunifásitì ìlú Benin fún odún mefa.

Grace Alele-Williams
OON, FMAN, FNAE
Ọjọ́ìbíGrace Alele
(1932-12-16)16 Oṣù Kejìlá 1932
Warri, Western Region, Nigeria
Aláìsí25 March 2022(2022-03-25) (ọmọ ọdún 89)
ìpínlè Eko, Nàìjíríà
Ẹ̀kọ́PhD (mathematics)
Iléẹ̀kọ́ gígayunifásítì ìlú Ibadan
University of Chicago
Olólùfẹ́
Babatunde Abraham Williams
(m. 1963; died 2010)
Àwọn ọmọ5

Àárò Ayé Àti Èkó Rè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abí Grace Alele sí ìlú Warriìpinlè Delta, orílè-èdè Nàìjíríà, óka ìwé ní ilé-ìwé Ìjoba ni ìlú Warri, Queen's College ní Èkó, òsì tún kawe ní ilé-ìwé giga yunifásitì ìlú Ìbàdàn [3], ó gba master degree rè ninú Mathi nígbà tí ósì ún se isé olûkó ní Queen's School ìlú Ede ní ìpinlè Osun ni odun 1957, ótún gba àmì èye Dokita(PhD) ní Yunifásitì tí Chicago(orílè-èdè Amerika) ní odun 1963, èyí tí ómú kí ójé obinrin àkókó ní Nàìjirià láti gba ami eye Dokita(Doctorate degree).

Grace Alele-Williams

Ìgbé Ayé rè Gegebi Omowe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Grace Alele bèrè sí ún sisé olùkó ní ilé-ìwé Queen's College ni Ede, ìpínlè Osun, ibi tí o tijé olùkó láti odun 1954 dé 1957 [4]. Òfi ibè kalè láti losí yunifásitì ti Vermont níbi tí oti padà di igbekeji Ojogbon, léyìn náà, o sisé ní Yunifásitì ìlú Ibadan, ósì tún sisé ní Yunifásitì Ìlú Èkó níbi tí àti só di Òjògbón nínú ìmò Mathi. [5]. Óní ìfé gidigidi fún èkó fún awon obinrin, Grace Alele dí olori yunifásitì ìlú Benin ní odun 1985, eyi tí osodi obinrin tí okoko di adari yunifásitì ní Nàìjirià [6]

Alele Williams fé Babatunde Abraham Williams(tí a bí ní odun 1932) ní 1963, léyìn ìgbà tí o padà wá láti Ìlú Amerika, Alele ní omo marun, ósì ti ni omo-omo mewa ní odun 2017 [7], ófi ayé sílè ní ojó March 25, 2022 [8]

Àwon Àtèjáde Rè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Dynamics of Curriculum Change in Mathematics - Lagos State Modern Mathematics Project. [9]
  2. Education of Women for National Development. [10]
  3. Report: The Entebbe Mathematics Project. [11]
  4. The Development of Modern Mathematics Curriculum in Africa. [12]
  5. Education and Government in Northern Nigeria. [13]
  6. Education and Status of Nigerian Women.
  7. Major Constraints to Women's Access to Higher Education in Africa. [14]
  8. The Politics of Administering a Nigerian University.
  9. The Political Dilemma of Popular Education: An African Case.[15]
  1. "Grace Alele-Williams: Mathematician who dealt with cultism at UNIBEN". Vanguard News. 2018-04-14. Retrieved 2022-03-27. 
  2. Wahab, Bayo (2018-03-08). "5 women who have made their marks in education". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-03-27. 
  3. "Minimum Wage: NASS Is Ready, Waiting For Executive-Saraki". SilverbirdTV. 2017-08-04. Archived from the original on 1 April 2022. Retrieved 2022-03-27. 
  4. "Grace Alele Williams". Women Mathematicians. 1932-12-16. Retrieved 2022-03-27. 
  5. "AMU CHMA NEWSLETTER #12 (03/27/1994)". University at Buffalo. 1993-09-19. Retrieved 2022-03-27. 
  6. Agboke, Anuoluwapo (2018-04-12). "First Female Vice Chancellor in Nigeria". Hintnaija. Archived from the original on 27 April 2021. Retrieved 2022-03-27. 
  7. "Grace Alele, Role Model,Teacher, Professor, Docror, Vice-chancellor, Warrior, Prominent Nigerian, Nigeria Personality Profiles". Nigeriagalleria. 1932-12-16. Retrieved 2022-03-27. 
  8. Egbejule, Michael; City, Benin (2022-03-26). "First female VC, Prof. Grace Alele-Williams, dies at 89 - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 27 March 2022. Retrieved 2022-03-27. 
  9. Williams, Grace Alele. "Dynamics of Curriculum Change in Mathematics--Lagos State Modern Mathematics Project.". West African Journal of Education. https://eric.ed.gov/?id=EJ112796. Retrieved 2022-03-27. 
  10. Alele-Williams, G. "Education of Women for National Development". AfricaBib. Retrieved 2022-03-27. 
  11. Williams, Grace Alele. "Report: The entebbe mathematics project". International Review of Education 17 (2): 210–214. doi:10.1007/BF01421114. https://ui.adsabs.harvard.edu/abs/1971IREdu..17..210W/abstract. Retrieved 2022-03-27. 
  12. Williams, Grace A. Alele (1976-04-01). "The development of a modern mathematics curriculum in Africa". The Arithmetic Teacher 23 (4): 254–261. doi:10.5951/AT.23.4.0254. https://pubs.nctm.org/view/journals/at/23/4/article-p254.xml. Retrieved 2022-03-27. 
  13. "REVUE PRESENCE AFRICAINE N° 87". Présence Africaine Editions (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-03-27. 
  14. Alele-Williams, G. "Major Constraints to Women's Access to Higher Education". AfricaBib. pp. 71–76. Retrieved 2022-03-27. 
  15. Chukunta, N. K. Onuoha (1978). "Education and National Integration in Africa: A Case Study of Nigeria". African Studies Review (Cambridge University Press) 21 (2): 67–76. ISSN 15552462 00020206, 15552462. JSTOR 523662. http://www.jstor.org/stable/523662. Retrieved 2022-03-27.