C. V. Raman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Sir Chandrasekhara Venkata Raman, FRS

Ìbí 7 Oṣù Kọkànlá, 1888(1888-11-07)
Thiruvanaikoil, Tiruchirappalli, Madras Presidency, British India
Aláìsí 21 Oṣù Kọkànlá, 1970 (ọmọ ọdún 82)
Bangalore, Karnataka, India
Ọmọ orílẹ̀-èdè Indian
Ẹ̀yà Tamil
Pápá Physics
Ilé-ẹ̀kọ́ Indian Finance Department
Indian Association for the Cultivation of Science
Indian Institute of Science
Ibi ẹ̀kọ́ University of Madras
Doctoral students G. N. Ramachandran
Ó gbajúmọ̀ fún Raman effect
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí Knight Bachelor (1929)
Nobel Prize in Physics (1930)
Bharat Ratna (1954)
Lenin Peace Prize (1957)
Religious stance Hindu

Sir Chandrasekhara Venkata Raman, FRS (Tàmil: சந்திரசேகர வெங்கடராமன்) (7 November 1888 – 21 November 1970) je asefisiksi ara India ti ise ni ipa ninu idagba sayensi ni India. O gba Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì ni 1930 fun iwari pe nigbati itanmole ba gba oju eroja geere, awon melo ninu imole na to je titakuro yio ni iyipada ninu ibuiru (wavelength) won.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]