Erwin Schrödinger

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Erwin Schrödinger
ÌbíErwin Rudolf Josef Alexander Schrödinger
(1887-08-12)12 Oṣù Kẹjọ 1887
Erdberg de, Vienna, Austria-Hungary
Aláìsí4 January 1961(1961-01-04) (ọmọ ọdún 73)
Vienna, Austria
Ará ìlẹ̀Austria, Germany, Ireland
Ọmọ orílẹ̀-èdèAustria
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Breslau
University of Zürich
Humboldt University of Berlin
University of Oxford
University of Graz
Dublin Institute for Advanced Studies
Ghent University
Ibi ẹ̀kọ́University of Vienna
Doctoral advisorFriedrich Hasenöhrl
Other academic advisorsFranz S. Exner
Friedrich Hasenöhrl
Notable studentsLinus Pauling
Felix Bloch
Ó gbajúmọ̀ fúnSchrödinger equation
Schrödinger's cat
Schrödinger method
Schrödinger functional
Schrödinger picture
Schrödinger-Newton equations
Schrödinger field
Rayleigh-Schrödinger perturbation
Schrödinger logics
Cat state
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1933)
Signature
Ere ori Schrödinger, ni agbala ile akoko University of Vienna, Austria.

Erwin Rudolf Josef Alexander Schrödinger (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈɛrviːn ˈʃrøːdɪŋɐ]; 12 August 1887, Erdberg – 4 January 1961, Vienna) je ara Ostria to je onimo fisiksi oniriro to gbajumo fun afikun re si isise ero ayosere, agaga isodogba Schrödinger, fun eyi to gba Ebun Nobel ni 1933. Ninu awon leta ni 1935 si ore re Albert Einstein, o damoran adanwo ironu olongbo Schrödinger.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]