Cachupa
Type | Stew |
---|---|
Place of origin | Cape Verde |
Main ingredients | Fish or meat (sausage, beef, goat, or chicken), hominy, beans |
c. 100-200 kcal | |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Cachupa (pt, Cape Verdean Creole Katxupa IPA: [kɐˈʧupɐ]) jẹ́ oúnjẹ tó gbajúmọ̀ ní àgbègbè Cape Verde, ní Ìwọòrùn Áfríkà. Ó jẹ́ ọbẹ̀ tí wọ́n máa ń sè ní orí iná tí a yí lọ ilẹ̀, tí ó sì máa ń ní àwọn èròjà bíi àgbàdo, ẹ̀wà, ọ̀dùnkún, ẹ̀gẹ́, ẹja tàbí ẹran yálà ẹran màlúù adìyẹ, ewúrẹ́ tàbí ẹlẹ́dẹ̀ àti ..ọ́ máa ń pe oúnjẹ yìí ni oúnjẹ tí gbogbo orílẹ-èdè Cape Verde nífẹ̀ sí.[1][2] Gbogbo àdúgbò Cape Verde ló ní bí wọ́n ṣe máa ń sèé yàtọ̀. cròjà tí a kọ sókè yìí jẹ́ ti cachupa rica èyíctí ó nílò èròjà ju cachupa pobre. tí kò nílò èròjà púpọ̀
Cachupa guisada
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Èyí tó bá ṣẹ́kù nínú Katchupa ni wọ́n sábà máa ń tún dín, èyí sì ni wọ́n máa ń pè ní Katchupa frita, cachupa guisada tàbí cachupa refogada, tó túmọ̀ sí "Katchupa díndín".[3][4] A lè jẹ oúnjẹ yìí láàrọ̀ pẹ̀lú ẹyin dídín àti sọ́séèjì tàbí koté díndín.[5][6][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ King, Russell (2001). The Mediterranean Passage: Migration and New Cultural Encounters in Southern Europe.. Liverpool University Press. p. 104. ISBN 0-85323-646-1. https://books.google.com/books?id=dPiaOiPH5OYC.
- ↑ Raymond Almeida. "Cachupa di Cabo Verde". UMassD. Archived from the original on 2006-12-05. Retrieved 2006-12-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Recipes for Katchupa" (in Èdè Pọtogí). SAPO CV. Archived from the original on 2017-12-30. Retrieved 2017-01-15. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ [1] [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Mae Preta". Pt.livinginlisbon.com (in Èdè Pọtogí). Archived from the original on 2011-08-25. Retrieved 2010-03-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Sabor Crioulo". Tv1.etp.pt (in Èdè Pọtogí).
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2017-09-24. Retrieved 2017-01-15. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)