Claude Lévi-Strauss
Appearance
Claude Lévi-Strauss | |
---|---|
Orúkọ | Claude Lévi-Strauss |
Ìbí | Brussels, Belgium | 28 Oṣù Kọkànlá 1908
Aláìsí | 30 October 2009 Paris, France | (ọmọ ọdún 100)
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Structuralism |
Ìjẹlógún gangan | Anthropology Society Kinship Linguistics |
Àròwá pàtàkì | Structuralism Mythography Culinary triangle Bricolage |
Ipa látọ̀dọ̀
| |
Claude Lévi-Strauss (klod levi stʁos; 28, November, 1908 - 30, October, 2009) je onímọ̀ẹ̀dá-ènìyàn (anthropologist) ati onímọ̀ẹ̀yà-ènìyàn (ethnologist) ara ile Fransi, be si ni o je ikan ninu awon omowe pataki ni orundun 20un ti o se ifilole iro nipa structuralism.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |