Jump to content

Command and Staff College, Jaji

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Armed Forces Command and Staff College
Established1976
TypeStaff college
Parent institutionNational Defence College, Nigeria
Religious affiliationNigerian Armed Forces
CommandantAir vice-marshal Ebenezer Olayinka Alade
LocationIgabi, Kaduna StateJaji, Naijiria, Naijiria
CampusRural
Websiteafcsc.mil.ng

Armed Forces Command and Staff College, Jaji jẹ́ ilé-ìgbẹ̀kọ́ fún àwọn Nigerian Armed Forces pẹ̀lú àwọn ajagun orí òfurufú àti abẹ́-omi. Ó súnmọ́ ìlú Jaji, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní apá àríwá ilẹ̀ Kàdúná lábẹ́ ìjọba ìpínlẹ Igabi. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Air Vice Marshal Ebenezer Olayinka Alade ló ń darí ilé-ìwé náà.[1]

The Armed Forces Command and Staff College jẹ́ ilé-ìwé tí wọ́n dá sílẹ̀ ní oṣù karùn-ún, ọdún 1976, pẹ̀lú iṣẹ́ akọ́ni àgbà méjì. Ní oṣù kẹrin, ọdún 1978, ilé-ìwé náà gbòrò si nígbà tí wọ́n dá ẹ̀ka àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ kalẹ̀.[1] Oṣù kẹjọ, ọdún 1981 ni wọ́n fi ẹ̀kọ́ àwọn ológun ti abẹ́-omi kún ètò-ẹ̀kọ́ ilé-ìwé náà.[2]

Ètò-ẹ̀kọ́ àwọn adarí àgbà dálé lórí àwọn ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí nínú ètò-ẹ̀kọ́ àwọn Britain, ti British Army Staff College, ní Camberley.[2]

Ní oṣù kẹjọ, ọdún 2005, adarí àwọn ọmọ-ológun ti òkè-òkun, Adams Ingram yọjú sí Jaji, ó sì gbé owó tó tó bíi 200,000 pounds kalẹ̀ láti fi ran ilé-ìwé náà lọ́wọh.[3] Ní oṣù kọkànlá ọdún 2006, ọmọọba ti ìlú Wales láti ìlú United Kingdom wá sí Nàìjíríà láti wá ṣe àbẹ̀wò sí àwọn ológun tó wà ní Jaji.[4]

Àwọn òṣìṣẹ́ tó lààmìlaka

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn tó ti ṣetán tó ti lààmìlaka

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Armed Forces Command and Staff College (AFCSC) Jaji". Armed Forces Command and Staff College (AFCSC) Jaji. Retrieved 2021-05-02. 
  2. 2.0 2.1 "Nigeria - Training". Federal Research Division of the Library of Congress. Retrieved 2009-11-18. 
  3. "PRESS NOTICE: UK trains an extra 17,000 Nigerian peacekeepers". UK Ministry of Defence. 20 September 2005. Archived from the original on 24 March 2010. Retrieved 2009-11-18. 
  4. "The Prince of Wales visits Nigeria". Prince of Wales. 29 November 2006. Retrieved 2009-11-18.