Ìpínlẹ̀ Bàyélsà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ipinle Bayelsa
State nickname: Glory of all lands
Location
Location of Bayelsa State in Nigeria
Statistics
Governor
(List)
Seriake Henry Dickson (PDP)
Date Created 1 October 1996
Capital Yenagoa
Area 10,773 km²
Ranked 27th
Population
1991 Census
2005 est.
Ranked 35th

N/A
1,998,349
ISO 3166-2 NG-BY

Ipinle Bayelsa jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìpínlẹ̀ 36 tó wà ní orílè-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ìpínlẹ̀ Bayelsa sílẹ̀ ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1996. Ọ̀gbẹ́ni Seriake Henry Dickson tí ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Bayelsa tí ó ń palẹ̀mọ́ láti kúrò ti Ọ̀gbẹ́ni David Lyon tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn lábẹ́ ẹgbẹ́ àsíyá All Progressives Congress yóò gba ọ̀pá àṣẹ láti di Gómìnà ìpínlẹ̀ náà.[1] [2] [3] Yenagoa ni Olú-ìlú ìpínlẹ̀ Bayelsa.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. James, Akam (2019-11-28). "Bayelsa Governor-elect, David Lyon sets up 59-member transition committee - Daily Post Nigeria". Daily Post Nigeria. Retrieved 2019-11-30. 
  2. "APC dislodges PDP in Bayelsa, wins governorship election". Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2019-11-30. 
  3. "History of Bayelsa State". PropertyPro Insider. 2017-07-14. Retrieved 2019-11-30. 
  4. "Bayelsa State History, Tourist Attractions, Hotels & Travel Information". Guide to Nigeria tourism, local culture & investments. 2011-03-13. Retrieved 2019-11-30. 

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]