David Ferrer

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
David Ferrer
Ferrer Ready.jpg
Ferrer at the 2011 Australian Open.
Orílẹ̀-èdè  Spéìn
Ibùgbé Valencia, Spain
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹrin 2, 1982 (1982-04-02) (ọmọ ọdún 37)
Xàbia, Alicante, Spain
Ìga 1.75 m (5 ft 9 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 2000
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó $17,049,089
Ẹnìkan
Iye ìdíje 488–246
Iye ife-ẹ̀yẹ 18
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 4 (February 25, 2008)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 5 (November 12, 2012)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà SF (2011)
Open Fránsì SF (2012)
Wimbledon QF (2012)
Open Amẹ́ríkà SF (2007, 2012)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATP F (2007)
Ìdíje Òlímpíkì 3R (2012)
Ẹniméjì
Iye ìdíje 61–95
Iye ife-ẹ̀yẹ 2
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 42 (October 24, 2005)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà 3R (2005)
Open Fránsì 2R (2009)
Wimbledon 1R (2003, 2004, 2005, 2006, 2009)
Open Amẹ́ríkà 2R (2004, 2006)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje Òlímpíkì SF - 4th place (2012)
Last updated on: September 20, 2012 by Asmazif.

David Ferrer Ern (Valencian pronunciation: [daˈvit feˈreɾ ˈɛɾn]; ojoibi April 2, 1982 ni Xàbia, Alicante, Valencian Community) je osise agba tenis ara Spein to wa ni ipo nomba 5 Lagbaye ni ori ito ATP, ohun ni ara Spein keji ti ipo re gajulo leyin No. 4 Lagbaye Rafael Nadal.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]