Rafael Nadal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Rafael Nadal
Rafael Nadal in La Moneda-007.jpg
Rafael Nadal (2013).
Orúkọ Rafael Nadal Parera
Orílẹ̀-èdè Spéìn Spain
Ibùgbé Manacor, Majorca, Balearic Islands, Spain
Ọjọ́ìbí 3 Oṣù Kẹfà 1986 (1986-06-03) (ọmọ ọdún 31)
Manacor, Majorca, Balearic Islands, Spain
Ìga 1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 2001
Ọwọ́ ìgbáyò Left-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó

$50,061,827

Ẹnìkan
Iye ìdíje 619–124 (83.31%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 60
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (18 August 2008)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 1 (9 June 2014)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà W (2009)
Open Fránsì W (2005, 2006, 2007, 2008, 2010, 2011, 2012, 2013, 2014)
Wimbledon W (2008, 2010)
Open Amẹ́ríkà W (2010, 2013)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATP F (2010)
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal.svg Gold Medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje 102–60
Iye ife-ẹ̀yẹ 8
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 26 (8 August 2005)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 400 (20 May 2013)[1]
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà 3R (2004, 2005)
Wimbledon 2R (2005)
Open Amẹ́ríkà SF (2004)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Davis Cup W (2004, 2008, 2009, 2011)
Last updated on: 20 May 2013.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún  Spéìn
Men's Tennis
Wúrà 2008 Beijing Singles

Rafael "Rafa" Nadal Parera (Catalan: [rəˈfɛɫ nəˈðaɫ pəˈɾeɾə]; Spanish: [rafaˈel naˈðal paˈɾeɾa]) (ojoibi 3 June 1986) je omo Spani agba tenis alagbase to wa ni ipo kinni lagbaye. Nadal ti gba ife eye awon enikan Grand Slam mejo, eso wura 2008 Olympiki fun awon enikan, o ni record 18 fun awon idije ATP World Tour Masters 1000 o si tun je ara egbe Ife Eye Davis Spein to bori opin idije ni 2004, 2008 ati 2009. O je gbigba bi ikan ninu awon agba tenis to lokiki julo laye.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]