Althea Gibson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Althea Gibson
Althea Gibson in 1956.
Orílẹ̀-èdèUSA USA
Ìga1.80 m (5 ft 11 in)
Ọwọ́ ìgbáyòtennis
Ẹnìkan
Iye ìdíje0–0
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàF (1957)
Open FránsìW (1956)
WimbledonW (1957, 1958)
Open Amẹ́ríkàW (1957, 1958)
Ẹniméjì
Iye ìdíje0–0
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàW (1957)
Open FránsìW (1956)
WimbledonW (1956, 1957, 1958)
Open Amẹ́ríkàW (1957)

Althea Gibson (August 25, 1927 – September 28, 2003) je obinrin elere idaraya eni iye 1 lagbaye ara Amerika to je obinrin omo Afrika Amerika akoko to kopa ninu idije tenis lagbaye ati eni akoko to bori lati gba ife eye Grand Slam ni 1956. Won unpe nigba miran bi "Jackie Robinson ti tenis" nitoripe o mu opin wa si iwa "eleyameya ninu tenis."

Igbesiaye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi ni August 25, 1927 ni Silver, Clarendon County, South Carolina fun Daniel ati Annie Bell Gibson, Althea ni awon aburo meji, Daniel Jr. (to je mimi bi "Bubba"), ati Mildred ti se obinrin.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]