Pete Sampras

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Pete Sampras
Pete Sampras (2008) 1, cropped.jpg
Orílẹ̀-èdè Àdàkọ:U.S.
Ibùgbé Lake Sherwood, California
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹjọ 12, 1971 (1971-08-12) (ọmọ ọdún 48)
Potomac, Maryland
Ìga 1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 1988
Ìgbà tó fẹ̀yìntì 2002
Ọwọ́ ìgbáyò Owo otun (owo kan eyin-owo)
Ẹ̀bùn owó

$43,280,489

Ilé àwọn Akọni 2007 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje 762–222 (77.43%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 64
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (April 12, 1993)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà W (1994, 1997)
Open Fránsì SF (1996)
Wimbledon W (1993, 1994, 1995, 1997, 1998, 1999, 2000)
Open Amẹ́ríkà W (1990, 1993, 1995, 1996, 2002)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATP W (1991, 1994, 1996, 1997, 1999)
Ìdíje Òlímpíkì 3R (1992)
Ẹniméjì
Iye ìdíje 64–70 (47.76%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 2
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 27 (February 12, 1990)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà 2R (1989)
Open Fránsì 2R (1989)
Wimbledon 3R (1989)
Open Amẹ́ríkà 1R (1988, 1989, 1990)
Last updated on: October 23, 2012.

Peter "Pete" Sampras ( /ˈsæmprəs/; ojoibi August 12, 1971) ni ara Amerika to ungba tenis to ti feyinti ati eni ipo No. 1 Lagbaye tele. Nigba odun 14 to fi gba tenis ATP, o gba ife-eye Grand Slam 14 awon enikan besini o je gbigba bi ikan ninu awon agba tenis to lokiki julo lailai.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]