Jump to content

Boris Becker

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Boris Becker
Orílẹ̀-èdèWest Germany (1983–1990)
Jẹ́mánì Jẹ́mánì (from 1990)
IbùgbéSchwyz, Switzerland
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kọkànlá 1967 (1967-11-22) (ọmọ ọdún 57)
Leimen, West Germany
Ìga1.90 m (6 ft 3 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1984
Ìgbà tó fẹ̀yìntì30 June 1999
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$25,080,956
Ilé àwọn Akọni2003 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje713–214 (76.91%)
Iye ife-ẹ̀yẹ49
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (28 January 1991)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (1991, 1996)
Open FránsìSF (1987, 1989, 1991)
WimbledonW (1985, 1986, 1989)
Open Amẹ́ríkàW (1989)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPW (1988, 1992, 1995)
WCT FinalsW (1988)
Ìdíje Òlímpíkì3R (1992)
Ẹniméjì
Iye ìdíje254–136
Iye ife-ẹ̀yẹ15
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 6 (22 September 1986)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàQF (1985)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje Òlímpíkì Ẹ̀sọ́ Wúrà (1992)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Davis CupW (1988, 1989)
Hopman CupW (1995)
Last updated on: January 23, 2012.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Men's Tennis
Wúrà 1992 Barcelona Men's doubles

Boris Franz Becker (ojoibi 22 November 1967) je agba tenis to ti feyinti to je Eni Ipo 1 Lagbaye tele lati orile-ede Jemani. O gba ife-eye Grand Slam ni emefa bi enikan, eso Wura kan ninu idije enimeji ni Olimpiki, ati eni ti ojo-ori re kerejulo to gba Idije Wimbledon awon okunrin enikan nigba to je omo-odun 17.