Novak Djokovic

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Novak Djokovic
Novak Djokovic Miami 2012.jpg
Orúkọ Novak Đoković
Orílẹ̀-èdè Sérbíà Sérbíà
Ibùgbé Mónakò Monte Carlo
Ọjọ́ìbí 22 Oṣù Kàrún 1987 (1987-05-22) (ọmọ ọdún 28)
Belgrade, Sérbíà
Ìga 1.88 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 2003
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó $ 38.120.025
Ẹnìkan
Iye ìdíje 435–118 (78.70%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 30
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (4 July 2011)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 2 (16 July 2012)[1]
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà W (2008, 2011, 2012, 2013, 2015)
Open Fránsì F (2012)
Wimbledon W (2011, 2014)
Open Amẹ́ríkà W (2011)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATP W (2008)
Ìdíje Òlímpíkì Bronze medal.svg Bronze medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje 31–44
Iye ife-ẹ̀yẹ 2
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 114 (30 November 2009)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ No. 542 (28 May 2012)[2]
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà 1R (2006, 2007)
Open Fránsì 1R (2006)
Wimbledon 2R (2006)
Open Amẹ́ríkà 1R (2006)
Last updated on: 20 July 2012.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún  Sérbíà
Men's Tennis
Bàbà 2008 Beijing Singles

Novak Djokovic (Kirilliki Serbia: Новак Ђоковић; Novak Đoković; Àdàkọ:IPA-sh; ibi ni Belgrade ojoibi Oṣù Kàrún 22, 1987(1987-05-22)) je agba tenis alagbase ara Sérbíà, to di Ipo No. 1 ATP mu lati 4 July 2011 de 8 July 2012. Djokovic ti gba ife eye awon enikan Grand Slam mejo, o awon ife-eye idije ATP World Tour Masters 1000 12, o si tun je omo-egbe Ife Eye Davis Sérbíà to bori ni 2010. Opo awon olutuwo ere-idaraya, olugbewo tenis, ati awon atayo lowo ati tele gba pe Djokovic ni atayo tenis to gbokikijulo.[3][4][5][6][7]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àdàkọ:Link FA

Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA Àdàkọ:Link FA