Arthur Ashe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Arthur Ashe
Arthur Ashe
Orílẹ̀-èdèUSA USA
IbùgbéPetersburg, Virginia
Ìga6 ft 1 in (1.85 m)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1969
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1980
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed; one-handed backhand
Ẹ̀bùn owóUS$2,584,909
Ilé àwọn Akọni1985 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje818-260
Iye ife-ẹ̀yẹ33
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (1969)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (1970)
Open FránsìQF (1970, 1971)
WimbledonW (1975)
Open Amẹ́ríkàW (1968)
Ẹniméjì
Iye ìdíje315–173
Iye ife-ẹ̀yẹ18
Last updated on: July 24, 2007.

Arthur Robert Ashe, Jr.(July 10, 1943 – February 6, 1993) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfasẹ́ gbá tenis, tí wọ́n bí, tó dàgb̀a, sí Richmond, Virginia. Nípa iṣẹ́ bọ́ọ̀lù rẹ̀, ó jáwé olúborí tí ́ó sì gba ife-ẹ̀yẹ Grand Slam mẹ́ta, èyí tí ó sò di ìkan nínú àwọn tó dára jùlọ nínú tenis ní Amẹ́ríkà. Ashe, tí ó jẹ́ ọmọ Afrika Ameríkà, tún jẹ́ riranti fun akitiyan re fun ilosiwaju awujo.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]