David J. Wineland
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti David Jeffrey Wineland)
David J. Wineland | |
---|---|
David J. Wineland in 2008 | |
Ìbí | David Jeffrey Wineland 24 Oṣù Kejì 1944 Milwaukee, Wisconsin, USA |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | National Institute of Standards and Technology University of Colorado, Boulder |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley Harvard University University of Washington |
Doctoral advisor | Norman Foster Ramsey, Jr. |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (2012) National Medal of Science (2007) Schawlow Prize (2001) |
David Jeffrey Wineland[1] (ojoibi February 24, 1944)[2] je asefisiksi elebun Nobel ara Amerika to unsise ni ibi-idanwo fisiksi ni National Institute of Standards and Technology (NIST). Ninu awon ise to unse ni itesiwaju ninu isiseiwoju, agaga ifi laser mu ioni tutuninu apẹ̀rẹ̀ Paul ati ilo awon ioni inu apere lati samulo isise komputa quantum. O gba Ebun Noble ninu Fisiksi ni 2012, pelu Serge Haroche, fun “awon ona tuntun idanwo to se lo lati se iwon ati ifowoyipada awon sistemu quantum kookan”, to je nipa iwadi eruku imole, eyun awon fotoni.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedr1
- ↑ "Array of Contemporary American Physicists | David Wineland". Archived from the original on 2013-01-26. Retrieved 2012-10-27.
- ↑ "Press release - Particle control in a quantum world". Royal Swedish Academy of Sciences. Retrieved 9 October 2012. Text "title" ignored (help)