George Smoot

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
George Smoot
George Smoot at POVO conference in The Netherlands
ÌbíGeorge Fitzgerald Smoot III
Oṣù Kejì 20, 1945 (1945-02-20) (ọmọ ọdún 79)
Yukon, Florida, U.S.
IbùgbéFrance
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́UC Berkeley/LBNL/Université Paris Diderot-Paris 7
Ibi ẹ̀kọ́Massachusetts Institute of Technology
Doctoral advisorDavid H. Frisch[1]
Ó gbajúmọ̀ fúnCosmic microwave background radiation
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síAlbert Einstein Medal (2003)
Nobel Prize in Physics (2006)
Oersted Medal (2009)

George Fitzgerald Smoot III (ojoibi February 20, 1945) je ara Amerika aseseedaonirawo, aseoroidaye, elebun Nobel, ati eni to gba ebun owo $1 million lori idije ori TV (Are You Smarter Than a 5th Grader?). O gba Ebun Nobel fun Isiseeda ni 2006 fun ise re lori COBE pelu John C. Mather tto fa iwon "ida ara dudu ati anisotropy ti Iranka iruonikekere agbaye."

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Katherine Bourzac (12 January 2007). "Nobel Causes". Technology Review. Archived from the original on 2012-01-29. https://web.archive.org/web/20120129172243/http://www.technologyreview.com/article/17926/. Retrieved 2007-09-05. "And Smoot himself can still vividly recall playing a practical joke on his graduate thesis advisor, MIT physics professor David Frisch."