Serge Haroche

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Serge Haroche
Serge Haroche (May 2009)
Ìbí11 Oṣù Kẹ̀sán 1944 (1944-09-11) (ọmọ ọdún 79)
Casablanca, Morocco[1] (then a French protectorate)
Ọmọ orílẹ̀-èdèFransi
Ilé-ẹ̀kọ́Pierre-and-Marie-Curie University
Collège de France
Ibi ẹ̀kọ́École Normale Supérieure
Pierre-and-Marie-Curie University (Ph.D.)
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síCNRS Gold medal (2009)
Nobel Prize for Physics (2012)

Serge Haroche (ojoibi 11 September 1944)[1] je is a French asefisiksi ara Fransi to gba Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 2012 pelu David J. Wineland fun “awon ona tuntun idanwo to se lo lati se iwon ati ifowoyipada awon sistemu quantum kookan”, to je nipa iwadi eruku imole, eyun awon fotoni.[2][3] Lati 2001, Haroche je Ojogbon ni ile-eko giga Collège de France, ohun si ni Alaga Eka-Eko Fisiksi Quantum ni ibe.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Serge Haroche – Biographical". nobelprize.org. Retrieved 11 October 2012. 
  2. "Press release – Particle control in a quantum world". Royal Swedish Academy of Sciences. Retrieved 9 October 2012.  Text "title" ignored (help)
  3. Àdàkọ:Cite doi