Jump to content

Dice Ailes

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dice Ailes
Ailes showing his Gold slugs
Ọjọ́ìbíShasha Damilola Alesh
1 Oṣù Kẹjọ 1996 (1996-08-01) (ọmọ ọdún 28)
Orílẹ̀-èdèNigeian- Canadian
Iléẹ̀kọ́ gígaYork University
Iṣẹ́Singer, songwriter, rapper
Ìgbà iṣẹ́2014–present
Musical career
Irú orinPop, Afro pop, Afro hip-hop
Associated acts

Shasha Damilola Alesh tí orúkọ ìnagije rẹ̀ ń jẹ́ Dice Ailes, jé akọrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀, àti rápà. Ní oṣù keje, ọdún 2014, ó tẹwọ́ bòwé pẹ̀lú Chocolate City.[1] Wọ́n yàn án fún Rookie of the Year ní The Headies 2016.[2][3] Ní ọdún 2016, orin rẹ̀ TooXclusive ṣe àfihàn orin rè, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Miracle, ó sì wọ ipò kẹta nínú àwọn orin mẹ́wàá tó dára jù lọ fún oṣù kẹwàá.[4] Ní ọdún 2017, tooXclusive dárúkọ rẹ̀ lára àwọn olórin tó yẹ kí a mọ̀.[5]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ó ti kékọ̀ọ́ girama, ní ilé-ìwé girama Lagooz, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ ní Republic of Benin, àti Ghana kí ó tó kó lọ Canada níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ní York University. Ní ilé-ìwé gíga yìí ni ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ kí ó tó padà sí Nàìjíríà lẹ́yìn tí ó tẹwọ́ bòwé pẹ̀lú Chocolate City ní ọdún 2014.[6]

Ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nígbà tí ó darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ akọrin kan, pẹ̀lú Hyce- age, coker, Millie àti Reihnard nígbà tí ó wà nínú ẹgbẹ́ náà.[7] Ó di gbajúmọ̀ ní ọdún 2016, nígbà tí ó kọ orin "Miracle" pẹ̀lú Lil kesh.[8][9]

Ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù kejìlá, ọdún 2016, Dice Ailes kọrin pẹ̀lú WSTRN, Krept and Konan, Migos àti Lil kesh ní "Beat FM lọ́jọ́ ayẹyẹ kérésì" ní ọdún 2016 ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[10]

Àtòjọ àwọn orin rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
As lead artist
Year Title Album
2014 "Fantasy" Non-album single
"Telephone"
2015 "Machinery"
2016 "Miracle"
2017 "Ella"
2017 "Otedola"
2018 "mr biggs"
2018 "Dicey"
2018 "Enough"
2019 "Alakori"[11](feat. Falz)"Ginika"
2020 "Pim Pim" (feat Olamide)[12]
As featured artist
Year Title Album
2015 "Awon Temi"

(Loose Kaynon feat. Dice Ailes & Koker)

The Gemini Project[13][14]
2016 "Brooklyn"

(Ice Prince feat. Dice Ailes)

Jos to the World
2017 "Olohungbo"

(Masterkraft feat. Ceeza, YCEE & Dice Ailes)

Non-album single
"No Favors"[15]

(Yung6ix feat. Dice Ailes & Mr. Jollof)

2017 "Your Father"

(M.I Abaga feat. Dice Ailes)

Rendezvous
2019 "Que Cera”

(Vision DJ feat. Dice Ailes, Kwesi Arthur, Medikal)

As lead artist
Year Title Album
2015 "Drank"

(DJ Lambo, Milli, Dice Ailes)

TICBN
"Oh No No"

(Dice Ailes)

Year Title Released Date
2015 The Indestructible Choc Boi Nation 30 April 2015
As lead artist
Year Artist Title
2016 MI & Dice Ailes "Controlla (refix)"[16]

Àtòjọ àmì-ẹ̀yè tó gbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Event Prize Recipient Result
2015 tooXclusive Awards Best New Artiste[17] Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé[18]
2016 The Headies style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
2018 style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé[19]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Dice Ailes Joins Chocolate City". P.M. News. 11 July 2014. Retrieved 27 April 2017. 
  2. "Mayorkun Wins 'Rookie of the Year' Award at The Headies 2016". BellaNaija. Retrieved 27 April 2017. 
  3. "Mayorkun, Terry Apala or Dice Ailes: Who will win the Headies 2016 Rookie of the Year award?". Nigerian Entertainment Today. 19 December 2016. Retrieved 27 April 2017. 
  4. "Top 10 Songs for the Month Of October". WetinHappen Magazine. 7 November 2016. Archived from the original on 11 September 2018. Retrieved 27 April 2017. 
  5. "TooXclusive's Artistes To Watch in 2017!!!". tooXclusive. Archived from the original on 15 June 2017. Retrieved 19 May 2017. 
  6. "Chocolate City star Dice Ailes features Lil Kesh in new single 'Miracle' – Vanguard News". Vanguard. 10 October 2016. Retrieved 27 April 2017. 
  7. "Artiste of the week: Choc Boy, Diles Ailes – Tribune". Nigerian Tribune. 12 May 2017. Retrieved 19 May 2017. 
  8. Akan, Joey. "Dice Ailes will be a star with Miracle". Pluse Nigeria. Archived from the original on 29 April 2017. Retrieved 27 April 2017. 
  9. "Rising act, Millywine teams up with Dice Ailes on 'Run Up'". Vanguard Newspaper. 28 June 2020. Retrieved 19 September 2020. 
  10. Solanke, Abiola. "Migos: Hip hop group party with Nigerian teens at Beat FM Xmas concert". Pulse Nigeria. Archived from the original on 10 May 2017. Retrieved 29 April 2017. 
  11. "Listen: Falz And Dice Ailes Release New Catchy Tune "Alakori"". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News. 8 June 2019. Archived from the original on 9 June 2019. Retrieved 9 June 2019. 
  12. "Dice Ailes features Olamide on 'Pim Pim'". P.M News. 28 March 2020. Retrieved 19 September 2020. 
  13. "Loose Kaynon – The Gemini Project". cloud 9. Archived from the original on 27 March 2016. Retrieved 9 May 2017. 
  14. Base, MTV (12 January 2016). "News : loose kaynon releases "The Gemini Project"". MTV Base. Retrieved 9 May 2017. 
  15. "Yung6ix ft. Dice Ailes & Mr. Jollof – No Favors". 360nobs. Archived from the original on 9 May 2017. Retrieved 10 May 2017. 
  16. Solanke, Abiola. "New Music: M.I Abaga, Dice Ailes – "Controlla" (refix)". Pulse Nigeria. Archived from the original on 7 June 2016. Retrieved 29 April 2017. 
  17. "tooXclusive Awards 2015 Nominees List". tooXclusive. Retrieved 9 May 2017. 
  18. "tooXclusive AWARDS 2015 – WINNERS!". tooXclusive. Retrieved 9 May 2017. 
  19. Ohunyon, Ehis. "Wizkid, Davido, Simi and Mayorkun are among the big winners at the 12th edition of the Headies Music Awards.". Archived from the original on 4 July 2018. https://web.archive.org/web/20180704204722/https://www.pulse.ng/entertainment/music/headies-2018-winners-list-id8339846.html. 

Shasha Damilola Alesh dara julọ mọ nipasẹ orukọ ipele rẹ kú Ales,jẹ akọrin olorin ọmọ Naijiria kan, akọrin-akọrin ati olorin kan.Ni Oṣu Keje 2014, o fowo si akọsilẹ kan pẹlu Chocolate Ilu.[1] O pe fun Rookie ti ọdun ni pẹtẹlẹ pari ti ọdun 2016.[2] [3] Ni ọdun 2016, TooXclusive rẹ tun wa ni ipo aṣeyọri "Iyanu lori atokọ ti "Awọn orin 10 Top fun oṣu Oṣu Kẹwa". [4] Ni 2017, tooXclusive ti a npè ni bi "ọkan ninu awọn olorin ti o nilo lati mọ. [5]

Jabọ A kú kùnà Gbogbo ìgbà ló máa ń yẹ àwọn odi rẹ̀ wò Bi Shsha Damilola Alesh 1 August 1996 (ọjọ-ori 25) Orilẹ-ede Nigeian- Canada Alma Yunifasiti York Iyalẹnu olorin, akọrin Awọn ọdun ṣiṣẹ 2014–bayi Irinse orin Awon Agbejade, Afro agbejade, ibadi-akọrin Ni kutukutu igbesi aye ati ẹkọ Iṣẹ Igbadun Awọn ẹbun ati yiyan Wo tun Awọn itọkasi Awọn ọna asopọ ita Ni oṣu to kọja 7 sẹyin nipasẹ Kkbshow