Lil kesh
Lil Kesh | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Kẹ́shinró Ọlọ́ládé |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Lil kesh |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹta 1995 Ìpínlẹ̀ Èkó , Nàìjíríà |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, Nàìjíríà |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Drums and Vocals |
Years active | 2014- di àsìkò yìí |
Labels | |
Associated acts |
Kẹ́ṣhiró Ọlọ́ládẹ́ ( bí ní Oṣù kẹ́ta Ọjọ́ Kẹtàdínlógún, Ọdún 1995), tí àwọn ènìyàn mọ sí Lil Kesh, jẹ́ Olórin, Rápà àti Akọ-Orin Nàìjíríà. Ó di ìlú-mọ̀-ọ́-ká lẹ́yìn tó kọ orin "Shoki".[1][2]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kẹ́shinró Ọlọ́láde jẹ́ bíbí àti dàgbà sí Bàrígà, agbègbè kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní Nàìjíríà.
Ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó lọ sí Stockbridge College fún ẹ̀kọ́ pámárìlì àti ṣẹ́kọ́ndàrì, lẹ́yìn náà ó lọ sí Fáṣítì Èkó. Níbi tó tí kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀dá-èdè. Lẹ́yìn náà, Ó lọ sí National Open University, Nàìjíríà níbi tó ti kọ́ ẹ̀kọ́ Mass Communication lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì.
Ìṣe Ààjò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́-ààjò rẹ̀ ní ọdún 2012. Nígbà tó ń rápà láàárín àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ ní Bàrígà. Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ó kọ orin àkọ́kọ́ rẹ̀ "Lyrically", orin àkọ́kọ́ rẹ̀ yìí gbajúmọ̀ láàárín àwọn Fáṣítì Nàìjíríà. Àbábọ̀ rẹ̀, jẹ́ kí Lil Kesh Tọwọbọ̀wẹ́ pẹ̀lú Yahoo Boy No Laptop Nation tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí YBNL Nation (YBNL) tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ Olórin Aládàání tí Olùdálè rẹ̀ jẹ́ Ọlámìídé Adédèjì ní ọdún 2012. Lábẹ́ YBNL, ó kọ Shoki, Efejoku, Gbèsè àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó fi álíbọ̀mù àkọ́kọ́ rẹ̀ náà lẹ̀ tí ó jẹ' YAGI".
Álíbọ̀mù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Album details |
---|---|---|
2016 | Y.A.G.I |
|
Lára àwọn orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Album |
---|---|---|
2014 | "Lyrically" | Y.A.G.I |
"Shoki" | Non-album single | |
"Shoki (Remix)" (featuring Olamide & Davido) | ||
2015 | "Shoki (Female Version)" (featuring Cynthia Morgan, Chidinma, Eva Alordiah) | |
"Gbese" | ||
"Efejoku" | Y.A.G.I | |
"Is It Because I Love You?" (featuring Patoranking) | ||
2016 | "Ibile" | |
"Bend Down Select" | Non-album single | |
2018 | "Again O" | |
2018 | "Flenjor"(featuring Duncan Mighty) | |
2019 | "Undertaker"[3] | |
2020 | "All The Way"[4] | |
2020 | "Too Sweet"[5] |
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Abimboye, Micheal (24 December 2014). "Kiss Daniel, Lil Kesh others to rule 2015". Premium Times. http://www.premiumtimesng.com/arts-entertainment/173847-kiss-daniel-lil-kesh-others-rule-2015.html.
- ↑ "MUST WATCH! AMBER ROSE Dances To Lil Kesh’s ‘SHOKI’ At D’banj’s Concert". Information Nigeria. 1 February 2015. http://www.informationng.com/2015/02/must-watch-amber-rose-dances-to-lil-keshs-shoki-at-dbanjs-concert.html.
- ↑ "Audio: Lil Kesh Releases "Undertaker"". PM News. 19 February 2019. Retrieved 21 February 2019.
- ↑ "Audio: Lil Kesh Releases "All The Way"". PulseDigi. 24 September 2020. Retrieved 24 September 2020.
- ↑ "Lil Kesh – Too Sweet ft Chike". legitbaze. 24 September 2020. Archived from the original on 19 October 2021. Retrieved 24 September 2020.