Dogon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Dogon people
Dogon12.jpg
Dogon people, Mali
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
400,000 to 800,000
Regions with significant populations
Mali[1]
Burkina Faso[2]
Èdè

Dogon languages

Dogon Àwon ènìyàn bíi ìdajì mílíònù tí a bá pàdé ní ilè Mali àti Burkina Faso ni wón n so èdè yìí. Bendor-Samuel àti àwon ìyókù (1989) ni ó gbé àte yìí kalè. Ínú àte yìí, a rí ‘Proto Dogon’ ti o pín si ìsòrí mefa. Àwon ìsòrí náà nìwòn yìí

(a) Plain - Jamsay tegu, Toro teju, Tene ka, Tomo ka

(b) Escarpment Toro soo, Tombaco soo, Kamba soo

(d) West - Dulerí dom, Ejenge dó

(e) North west - Bangeri Me

(e) North Platean - Bondum dom. Dogul dom

(f) Ìsòrí kefà ni Yanda dom, Oru yille àti Naya tegu.

Iye àwon tí ó ń so èdè yìí je 100,000. (Òkémárùn-ún) Orílè èdè tí won tí ń so èdè yìí ni Mali, ati Burkina Faso


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]