Jump to content

Done P. Dabale

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Done Peter Dabale
Bishop
ChurchUnited Methodist Church in Nigeria (Christian)
Personal details
Born(1949-04-26)Oṣù Kẹrin 26, 1949
Nyabalang-Yotti, Jereng District, Adamawa State, Middle-Belt, Nigeria
DiedAugust 26, 2006(2006-08-26) (ọmọ ọdún 57)
Houston, Texas

Done Peter Dabale (tí wọ́n bí ní April 26, 1949, tó sì ṣaláìsí ní August 26, 2006) jẹ́ olùdásílẹ̀ ìjọ United Methodist Church ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà (UMCN).[1] Lásìkò tó jẹ́ bíṣọ́ọ̀bù, iye àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ ìjọ náà lọ láti 10,000 sí 400,000.[1]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ tó lọ ni:

 • 1967 Nursing Certificate, Numan School of Nursing ní Ìpínlẹ̀ Adámáwá, ní Nàìjíríà.[2]
 • 1970 Certificate in General Agriculture, Government Agriculture School ní Yola ìpínlẹ̀ Adamawa, Nàìjíríà.[2]
 • 1974 Diploma in Theology, Theological College ní Bukuru Jos, Nàìjíríà.[3]
 • 1980 International Diploma in Animal Husbandry, Barneveld College ní Netherlands[3]
 • 1980 Certificate in Church Administration, Gbarnga School of Theology ní Monrovia, Liberia[3]
 • 1985 Research Certificate in Agriculture and Theology, University of Alabama, USA[3]
 • 1987 Doctor of Divinity in Theology, Gbarnga School of Theology ní Monrovia, Liberia[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. 1.0 1.1 "First United Methodist Bishop in Nigeria, Done Peter Dabale, Dies in U.S Hospital". umc.org. United Methodist Church. August 27, 2006. Archived from the original on September 24, 2014. Retrieved September 26, 2014. 
 2. 2.0 2.1 "Bishop Done Peter Dabale (Nigeria Area), Recipient of the Distinguished Peacemaker Award - Africa". GBGM News Archives. General Board of Global Ministries, The United Methodist Church. Archived from the original on August 30, 2009. Retrieved September 26, 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 3. 3.0 3.1 3.2 3.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :02
 4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :1