Jump to content

Dorcas Shola-Fapson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Dorcas ṣọlá Fapson)
Dorcas Shola-Fapson
Presenting in 2018 for NdaniTV
Ìbí1991
London
Iṣẹ́Actress

Dorcas ṣọlá Fapson jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tó kó nínú ètò kan tí wọ́n pè ní ṣúgà lórí ìkànnì MTV's. [1]Àdàkọ:Circular reference as ‘Sophie’.[2][3] Lọ́dún 2020, ó padà sí ètò ṣúgà náà lórí ìkànnì MTV láti sọ̀rọ̀ lórí àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà pẹ̀lú àwọn òṣèré tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pọ̀ káàkiri ilẹ̀ adúláwọ̀ Áfíríkà

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Fapson nilui London ní nǹkan bí ọdún 1990s.[4] Ìyá rẹ̀ kú nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìnlá. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìṣe ọ̀daràn (Criminology) lórílẹ̀ èdè England. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ tíátà ní New York.

Ó kópa nínú ètò ṣúga abala kẹta ní ìkànnì MTV.[1] as ‘Sophie’[2][3] and she was the presenter of "The Juice" an interview series for NdaniTV.[5]

Ó wà nínú ètò ṣúgà ní ìkànnì MTV tí ó ó tún fi padà di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ìṣègùn tí wọ́n pè ní "Sophie" nínú ètò mìíràn tí wón pè ní MTV Shuga Alone Together níbi tí wọ́n ti ń sọ̀rọ̀ nípa àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà lọ́dún 2020.[6] The series was written by Túndé Aládéṣe and broadcast for several nights - its backers include the United Nations.[7] Àwọn ètò wọ̀nyí wà ní Nàìjíríà, South Africa, Kenya àti Côte d'Ivoire, tí ìtàn náà ń tẹ̀ síwájú lórí ìtàkùn ayélujára [8] who include Mohau Cele, Lerato Walaza, Sthandiwe Kgoroge, Uzoamaka Aniunoh, Mamarumo Marokane and Jemima Osunde.

Àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Shuga (season 3): Shuga Naija". Retrieved 11 January 2019. 
  2. 2.0 2.1 Odion Okonofua (30 January 2018). "Dorcas Shola-Fapson All you need to know about the actress". punch ng. Retrieved 11 January 2019. 
  3. 3.0 3.1 Kore Ogidan (2 September 2018). "I never planned to leave the US to act in Nigeria – Dorcas Shola-Fapson". punch ng. Retrieved 11 January 2019. 
  4. Olayinka (2018-01-02). "A Peek Into The Life Of Nollywood Actress, Dorcas Shola Fapson". INFORMATION NIGERIA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-18. 
  5. "THE JUICE S3E01 - FALZTHEBAHDGUY". Ndanitv on youtube. 18 May 2016. Retrieved 31 May 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "MTV Shuga: Alone Together | Episode 25". MTV Shuga on YouTube. 29 May 2020. Retrieved 31 May 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Every Woman Every Child partners with the MTV Staying Alive Foundation to Tackle COVID-19". Every Woman Every Child (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-16. Archived from the original on 9 October 2021. Retrieved 2020-04-30. 
  8. Akabogu, Njideka (2020-04-16). "MTV Shuga and ViacomCBS Africa Respond to COVID-19 with "Alone Together" Online Series". BHM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-30. 
  9. "Banana Island Ghost | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 6 October 2021. Retrieved 2020-05-31.