Dorcas Shola-Fapson
Dorcas Shola-Fapson | |
---|---|
Presenting in 2018 for NdaniTV | |
Ìbí | 1991 London |
Iṣẹ́ | Actress |
Dorcas ṣọlá Fapson jẹ́ òṣèrébìnrin àti atọ́kùn tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tó kó nínú ètò kan tí wọ́n pè ní ṣúgà lórí ìkànnì MTV's. [1]Àdàkọ:Circular reference as ‘Sophie’.[2][3] Lọ́dún 2020, ó padà sí ètò ṣúgà náà lórí ìkànnì MTV láti sọ̀rọ̀ lórí àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà pẹ̀lú àwọn òṣèré tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pọ̀ káàkiri ilẹ̀ adúláwọ̀ Áfíríkà
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Fapson nilui London ní nǹkan bí ọdún 1990s.[4] Ìyá rẹ̀ kú nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rìnlá. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìṣe ọ̀daràn (Criminology) lórílẹ̀ èdè England. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó sìn kàwé gboyè nínú ìmọ̀ tíátà ní New York.
Ó kópa nínú ètò ṣúga abala kẹta ní ìkànnì MTV.[1] as ‘Sophie’[2][3] and she was the presenter of "The Juice" an interview series for NdaniTV.[5]
Ó wà nínú ètò ṣúgà ní ìkànnì MTV tí ó ó tún fi padà di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ìṣègùn tí wọ́n pè ní "Sophie" nínú ètò mìíràn tí wón pè ní MTV Shuga Alone Together níbi tí wọ́n ti ń sọ̀rọ̀ nípa àjàkálẹ̀ àrùn kòrónà lọ́dún 2020.[6] The series was written by Túndé Aládéṣe and broadcast for several nights - its backers include the United Nations.[7] Àwọn ètò wọ̀nyí wà ní Nàìjíríà, South Africa, Kenya àti Côte d'Ivoire, tí ìtàn náà ń tẹ̀ síwájú lórí ìtàkùn ayélujára [8] who include Mohau Cele, Lerato Walaza, Sthandiwe Kgoroge, Uzoamaka Aniunoh, Mamarumo Marokane and Jemima Osunde.
Àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sinimá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Banana Island Ghost (2017)[9]
- The Essence (2019)
Tẹlifíṣàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Shuga (season 3): Shuga Naija (2013-2014, 2020)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Shuga (season 3): Shuga Naija". Retrieved 11 January 2019.
- ↑ 2.0 2.1 Odion Okonofua (30 January 2018). "Dorcas Shola-Fapson All you need to know about the actress". punch ng. Retrieved 11 January 2019.
- ↑ 3.0 3.1 Kore Ogidan (2 September 2018). "I never planned to leave the US to act in Nigeria – Dorcas Shola-Fapson". punch ng. Retrieved 11 January 2019.
- ↑ Olayinka (2018-01-02). "A Peek Into The Life Of Nollywood Actress, Dorcas Shola Fapson". INFORMATION NIGERIA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-18.
- ↑ "THE JUICE S3E01 - FALZTHEBAHDGUY". Ndanitv on youtube. 18 May 2016. Retrieved 31 May 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "MTV Shuga: Alone Together | Episode 25". MTV Shuga on YouTube. 29 May 2020. Retrieved 31 May 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Every Woman Every Child partners with the MTV Staying Alive Foundation to Tackle COVID-19". Every Woman Every Child (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-16. Archived from the original on 9 October 2021. Retrieved 2020-04-30.
- ↑ Akabogu, Njideka (2020-04-16). "MTV Shuga and ViacomCBS Africa Respond to COVID-19 with "Alone Together" Online Series". BHM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-30.
- ↑ "Banana Island Ghost | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 6 October 2021. Retrieved 2020-05-31.