Edinburgh Zoo
Ìrísí
Date opened | 1913 |
---|---|
Location | Edinburgh, Scotland |
Number of species | 171 |
Annual visitors | >600,000 |
Memberships | BIAZA, EAZA,WAZA |
Major exhibits | Giant pandas, penguins, koalas, chimpanzees, sun bears |
Website | edinburghzoo.org.uk |
Edinburgh Zoo, tẹ́lẹ̀tẹ́lè Scottish National Zoological Park, jẹ́ ọgbà ẹranko fun ìdárayá 82-acre (33 ha) kan tí kò sí fún èrè tí ó wà ní olúìlú Scotland. Wọ́n kọ́ọ ń ọdún 1913, tí ó sì jẹ́ pé Royal Zoological Society of Scotland lónii, ó máa ń gba èrò tí ó ju 600,000 lọ́dọọdún, tí ó sì jẹ́ kí ó jẹ́ ìkejì ibi tí ó lókìkí jùlọ ni Scotland tí wọ́n máa ń san owó làti wọlé[1]
Tùn wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Zoo Beginnings". Edinburgh Zoo. Archived from the original on 28 September 2007. Retrieved 15 June 2007.