Egbògi Alábùkún
Egbògi Alábùkún jẹ́ oògùn tí olóògbé Jacob Ṣógbóyèga Odùlatẹ̀ ṣàwárí rẹ̀ ní ọdún 1981, lásìkò tí ìmúnisìn àwọn Gẹ̀ẹ́sì ilẹ̀ Britain lágbara gidi. Oògùn yí .[1][2] Púpọ̀ nínú àwọn èlò oògùn yí ni wọ́n kó jọ láti ìlú Liverpool.
Àwọn èròjà inú egbògi náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn ohun èlò tí wọ́n fi se egbògi Alábùkún oníyẹ̀fun ni
- acetylsalicylic acid àti caffeine. Àwọn wọ̀nyí jẹ́ ojú-lówó jùlọ tí iye èròja acetylsalicylic acid sì jẹ́ 760 mg nígbàbtí èlò caffeine jẹ́ 60 mg tí àpapọ̀ èlò méjèjì yí jẹ́ 820 mg.
Ìwúlò egbògi yí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lára àwọn ohun tí wọ́n ma ń lo egbògi yí fún ni:
- gbọ̀fun gbọ̀fun (sore throat]],
- akokoro (thoothache),
- ẹ̀jẹ̀ dídì(blood cloth) ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[3]
Ìmọ̀ ìwádí ìjìnlẹ̀ ní oògùn ati egbògi sọ wípé Alábùkún ma ń dèna ìfúnpọ̀ tàbí dídìpọ̀ ẹ̀jẹ̀ ní agọ́ ara. Ó tun ń ṣiṣẹ́ fún ara ríro, ó sì ma ń jẹ́ kí ẹni tí ó bá lòó ó mí sókè sódò dára dára.
Ìpalára egbògi yí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n fi kun wípé bí a bá si egbògi yí lò, ó lè fa àwọn àìsàn wọ̀nyín nínú ara.:
Egbògi yí gbajúmọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ó ṣì fi wà lórí àtẹ láti nkan bí ọgọ́rún ùn ọdún sẹ́yìn tí tí di òní. Àwọn orílẹ̀-èdè bí Nàìjíríà, Benin Cameroon, Ghana àti àwọn agbègbè kọ̀ọ̀kan ní ilẹ̀ Europe náà ni wọ́n ti ń lo egbògi yí.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Admin. "The life and times of Jacob odulate". News Headlines. Retrieved 7 February 2017.
- ↑ Admin. "Yoruba who have made us proud". Yoruba Parapo. Retrieved 7 February 2017.
- ↑ EDWARD-EKPU, UWAGBALE. "The Nigerian pharmacist who invented alabukun powder 100 years ago". Science Tech Africa. Archived from the original on 7 February 2017. Retrieved 7 February 2017.