Jump to content

Jacob Ṣógbóyèga Odùlatẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jacob Ṣógbóyèga Odùlatẹ̀
Odulate in his chieftaincy regalia and wearing a saki (specially for chief) over his shoulder
Ọjọ́ìbíJacob Ṣógbóyèga Odùlatẹ̀
1884
Ìkòròdú, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Aláìsí1962
Creek Hospital, Oníkán, Ìpínlẹ̀ Èkó
IbùgbéAbẹ́òkúta; Ìpínlẹ̀ Ògùn
Orílẹ̀-èdèọmọ Nàìjíríà
Ẹ̀kọ́Elementary School until age of 12; self-taught since then
Iṣẹ́Olùdásílẹ̀
SuccessorṢẹ́gun Odùlatẹ̀
Àwọn ọmọDr Jacobson Oladele ODULATE (Eye Surgeon) Segun ODULATE (Physicist & Business Entrepreneur - Successfully ran Alabukun in 70's & 80's Folake Solanke
Albert Olukoya
Grand Children:Eldest - Julian Olayinka Olatokunbo ODULATE (m) Bola Odulate (f) Akin ODULATE (m) Koye ODULATE (f) I ODULATE (f) Toyin Odulate (f) Dayo Odulate (f) Gboly Odulate (m)

olóyè Jacob Ṣógbóyèga Odùlatẹ̀ (1884–1962), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Blessed Jacob jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pharmacist, olùdásílẹ̀, alápilẹ̀kọ, oníṣòwòàti olùdásílẹ̀ egbògi Alábùkún. [1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Jacob nínú ìdílé olórogún ní ìlú Ìkòròdú, sínú ẹbí alàgbà Odùlatẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1884. Bàba bàá rẹ̀ ni olóyè Odùkànmádé tí ó wá láti inú ẹbí Sẹnlú tí ó jẹ́ ẹ̀ka mọ̀lẹ́bí Ranodu tí ó jẹ́ ìdílé ọba nílú Ìmọ̀ta, ìlú tí ó súnmọ́ Ìkòròdú pẹ́kí pẹ́kí [2] Nígbà tí ó wà ní dédé ọmọ ọdún Mẹ́rìnlá, ó fẹsẹ̀ rìn lọ sílú Abẹ́òkútaÌpínlẹ̀ Ògùn, tí ìrìn náà sì gbàá ní odidi oṣù mẹ́ta gbáko kí tó dé Abẹ́òkúta. Lásìkò tí ó wà ní Abẹ́òkúta, ó ṣalábàá-pàdé onímọ̀ ìpo oògùn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Dókítà Ṣapará, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ṣẹ́ ìmọ̀ ìpo oògùn láti ọ̀dọ̀ rẹ̀.[3][4] Láìpẹ́, Jacob dá ilé iṣẹ́ ìpo oògùn tirẹ̀ tí ó pè ní egbògi Alábùkún, níbi tí ó ti ń po oríṣiríṣi oògùn àtinúdá tirẹ̀.[5].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]