Jump to content

Emeka Atuma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Emeka Atuma jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O ti ṣe aṣoju Ikwuano / Umuahiani Ile-igbimọ Aṣoju ṣòfin . [1] [2]

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Emeka Atuma wá láti agbègbè Ikwuano Local Government ni Abia State, Nàìjíríà. O gbà oye imọ-ẹrọ láti Ile-ẹkọ giga ti Calabar . [3]

Iṣẹ òṣèlú Atuma bẹrẹ nígbàtí o dibo si Ile-igbimọ Aṣoju ṣòfin ti onsójú àgbègbè Ikwuano/Umuahia lati odun 2003 si 2007. [4] [5]

Ni ọdun 2023, o díje fun Sẹnetọ to n ṣoju Abia Central gẹgẹ bi oludije ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC). [6] [7]

Ni osu kejila, ọdun 2024, Aare Bola Tinubu yan Atuma gẹ́gẹ́ bi alága ajo South East Development Commission (SEDC) ṣùgbọ́n Emeka Nworgu ropo e ni ko tii ju wákàtí mẹ́rìnlélógún leyin iyansipo naa. [8] [9]