Emmanuel Adekunle
Ìrísí
Emmanuel Oludaisi Adekunle jẹ́ bíṣọ́ọ́bù Ánglíkánì ní Nàìjíríà.[1] oun ní Bishop tí Ẹ̀gbá lọ́wọ́lọ́wọ́.[2]
Á bí Adekunle ní Abẹ́òkúta ní ọjọ́ kòkandínlógbón oṣù kẹ́tá ní ọdún 1962. Ó tí kàwé ní Abẹ́òkúta Grammar School, Federal Polytechnic Ilaro atí Emmanuel College of Theology and Christian Education, lbadan. Ó jẹ́ olùkọ́ni nígbà kan rí atí ẹnginíà, wọ́n sì yàn án sínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ ní ọdún 1993. Ó dí Kánónì ní ọdún 1999 àti diákónì àgbà ní ọdún 2001. Ní 2006, a yàn gẹ́gẹ́ bí Próvóstì tí Kàtídírà St Peter, Abẹ́òkúta. Wọ́n yà á sí mímọ́ lọ́jọ́ Àìkú, ọjọ́ kẹ́tàlélógún oṣù kẹjọ, ọdún 2009 ní ṣọ́ọ̀ṣì Katidira ti St. Jude, Ebute Metta, Èkó.[3]
Àwọn itọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Emmanuel Adekunle" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Anglican Communion Office. "Diocese - Nigeria - Egba". anglicancommunion.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-04.
- ↑ "The Rt Revd Emmanuel Adekunle on World Anglican Clerical Directory". World Anglican Clerical Directory (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-10.