Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Rt. Hon.

Femi Abdulhakim Gbajabiamila
Speaker of the House of Representatives of Nigeria
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
June 2019
AsíwájúYakubu Dogara
House Leader of the House of Representatives of Nigeria
In office
June 2015 – June 2019
AsíwájúOgor Okuweh
Minority Leader of the House of Representatives of Nigeria
In office
June 2011 – June 2015
Arọ́pòOgor Okuweh
Minority Leader of the House of Representatives of Nigeria
In office
June 2007 – June 2011
AsíwájúAhmed Salik
Member of the House of Representatives of Nigeria
In office
2003–2007
Asíwájúyakubu Dogara
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kẹfà 1962 (1962-06-25) (ọmọ ọdún 59)
Lagos State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)
ResidenceLagos
Alma materUniversity of Lagos
OccupationLegislature
Websitehttp://femigbajabiamila.com

Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1962 (June 25, 1962) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú, Agbẹjọ́rò àti Agbẹnusọ Ilé-Ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú, All Progressives Congress tí ó ń ṣojú ìpínlẹ̀ Èkó láti ìjọba ìbílẹ̀ Sùúrùlérè. [1] [2] [3] [4]

Aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹni-ọ̀wọ̀ Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà kàwé ní Igbobi College ní ìlú Yábàá, ní ìpínlẹ̀ Èkó, bákan náà ní King William's CollegeIsle of Man, United Kingdom,[5] Atlanta's John Marshall Law School, United States, àti ní University of Lagosìpínlẹ̀ Èkó.[6] [7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "THISDAYonline". BNW News. Retrieved 2020-01-13. 
  2. Assembly, Nigerian National (1962-06-25). "Federal Republic of Nigeria". National Assembly. Retrieved 2020-01-13. 
  3. "When encomiums poured in torrents for Femi Gbajabiamila in Lagos". Premium Times Nigeria. 2012-06-27. Retrieved 2020-01-13. 
  4. "Ahmed Lawan, Femi Gbajabiamila go lead Nigeria 9th National Assembly". BBC News Pidgin (in Kúẹ́ńjùà). 2019-06-11. Retrieved 2020-01-13. 
  5. Ibiam, Agha (2004-02-07). "Gbaja-Biamila: Shocked Beyond Belief...". Thisday (BNW). http://news.biafranigeriaworld.com/archive/2004/feb/07/0043.html. Retrieved 2007-11-11. 
  6. "Hon. Femi Gbaja Biamila". National Assembly website. National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2007-10-23.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Ibrahim, Abubakar Adam (2012-06-24). "Hon. Femi Gbajabiamila’s biography for launch – Daily Trust". Daily Trust. Retrieved 2020-01-13.