Jump to content

Federal College of Education, Iwo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Federal College of Education, Iwo
MottoIntegrity, Wisdom and optimism
Established2020
TypePublic
ProvostProfessor Rafiu Adebayo
LocationIwo, Osun State, Nigeria
ColoursGreen     
WebsiteOfficial website

Federal College of Education, Iwo jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àgbàláwẹ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà,[1] tí a fọwọ́sowọ́lé láti fúnni ní àmì ẹ̀yẹ National Certificate in Education (NCE) sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ṣàṣeyọrí.[2]

Ìgbìmọ̀ Àṣẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Liad Tella – Alákóso
  • Auwal Hassan – Ọmọ ìgbìmò
  • Hajia Amina Tagwai Aji – Ọmọ ìgbìmò
  • Sunday Agholor – Ọmọ ìgbìmò
  • A. A. Adewale – Àṣojú Ìjọba Àpapọ̀
  • L.B. Aremu – Àṣojú E
  • R. I. Adebayo – Provost/Ọmọ ìgbìmò
  • M. A. Yusuff – Akọ̀wé

Federal College of Education, Iwo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 2020 ní Ìwó, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, nípasẹ̀ àjọṣe àdúróṣinṣin ti Ààrẹ Muhammadu Buhari.[3][4] Kọ́lẹ́ẹ̀jì náà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ọ̀gbọ̀n (30) tuntun tí a dá sílẹ̀ nípasẹ̀ àjọṣe àdúróṣinṣin Buhari láti ìgbà tí ó ti jẹ́ alákòóso láti ọdún 2015.

Ní ọdún 2022, a fún kọ́lẹ́ẹ̀jì náà ní NGN 1.3 bíliọ̀nù láti inú isúná ètò ináwó. Ní Oṣù Kẹfà ọdún 2021, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, Olúwo Ilẹ́ Ìwó, fi Certificate of Occupancy (C of O), fún àwọn alákòóso ilé-ẹ̀kọ́ náà níbi ilẹ́ ti ilé-ẹ̀kọ́ náà.[5]

Àwọn alákòóso pàtàkì

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Prof. Rafiu Ibrahim Adebayo, Provost

Mr. Mugsit Aderibigbe Yussuf, Registrar

Dr. Adebayo Lasisi, Bursar

Dr. Mrs Funmi Iyanda, College Librarian

Ilé-ẹ̀kọ́ náà ń pèsè orísirísi àwọn ẹ̀kọ́ lábẹ́ àwọn ẹ̀ka wón yìí:

School of Arts and Social Sciences

School of Education

School of Languages

School of Science

School of Vocational Studies

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "FEDERAL COLLEGE OF EDUCATION IWO – IWO, OSUN STATE" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-29. 
  2. "Federal College of Education in Osun State - Part 2". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-10. Retrieved 2022-02-28. 
  3. "Federal College Of Education, Iwo Gets N1.3bn, To Commence Academic Activities Soon - Osun Rep". OsunDefender (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-06. Retrieved 2022-02-28. 
  4. Murta, Aleem (2020-05-15). "Iwo Gets College of Education". https://tell.ng/iwo-gets-college-of-education/?amp. 
  5. "FCE Iwo: Oluwo presents C of O to management team - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-28.