Femi Otedola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Femi Otedola
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kọkànlá 1962 (1962-11-04) (ọmọ ọdún 61)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Ẹ̀kọ́Olivet Baptist High School
Obafemi Awolowo University
Iṣẹ́Businessman
Olólùfẹ́Nana Otedola
Àwọn ọmọ4, including Temiloluwa Elizabeth Otedola
Parent(s)Sir Michael Otedola

Femi Otedola (ojobi 4 Osu kokanla odun 1962) je onisowo orile-ede Naijiria, oninuure, ati alaga tele fun Forte Oil PLC. Lówọ́lówó, Ó jé álágá Geregu Power PLC

Igbesi aye ibere[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wo bi Otedola ni ilu Ibadan, olu ilu ipinle Oyo, guusuiwoorun Naijiria, ninu idile Oloogbe Sir Michael Otedola, Gomina Ipinle Eko lati 1992 si 1993.[1]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ex-Lagos gov, Sir Michael Otedola, dies at 87". Vanguard News. 2014-05-05. Retrieved 2022-02-06.