Jump to content

Ferdinand Sarrien

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ferdinand Sarrien

Ferdinand Sarrien je Alakoso Agba ile Furansi tele. Ferdinand Sarrien je oselu ti ile farense fun odun meta. A bi ni ilu Bourbon- lancy ni sanne - et- laine. O si ku ni ile paris. O je olori igbinmo kan ti awon eleya dudu n dari.