Jump to content

René Viviani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
René Viviani

Jean Raphaël Adrien René Viviani jẹ́ Alakoso Agba ilẹ̀ Faransé tẹ́lẹ̀. A bíi ni ọjọ́ kẹjọ, oṣù kọkànlá ọdún 1863, ó sì jáde láyé ni ọjọ́ keje oṣù kẹ̀sán ọdún 1925.Àwọn Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]