Pierre Pflimlin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Pierre Pflimlin
Pierre Pflimlin par Claude Truong-Ngoc 1975.jpg
Alakoso ile Fransi
Lórí àga
14 May 1958 – 1 June 1958
Asíwájú Félix Gaillard
Arọ́pò Charles de Gaulle
14th Aare Ileigbimo Asofin Europe
Lórí àga
1984–1987
Asíwájú Piet Dankert
Arọ́pò Charles Henry Plumb
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 5 February 1907
Aláìsí 27 Oṣù Kẹfà, 2000 (ọmọ ọdún 93)
Strasbourg
Ẹgbẹ́ olóṣèlú MRP

Pierre Eugène Jean Pflimlin (pípè ní Faransé: [pjɛʁ flimlɛ̃][1]; 5 February 1907 - 27 June 2000) je ara Fransi oloselu oseluarailu elesin Kristi to di Alakoso Agba ni Igba Oselu Kerin fun ose die ni 1958, ko to di pe Charles de Gaulle ropo re ni May 1958.[2]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. The Little Plum
  2. Pierre Pfimlin, The Guardian, 28 June 2000